Àìsáyà 7:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Torí Damásíkù ni orí Síríà,Résínì sì ni orí Damásíkù. Kí ọdún márùndínláàádọ́rin (65) tó pé,Éfúrémù máa fọ́ túútúú, wọn ò sì ní jẹ́ èèyàn mọ́.+ Àìsáyà 8:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 torí kí ọmọ náà tó mọ bí wọ́n ṣe ń pe, ‘Bàbá mi!’ àti ‘Ìyá mi!’ wọ́n máa kó àwọn ohun àmúṣọrọ̀ Damásíkù àti ẹrù ogun Samáríà lọ níwájú ọba Ásíríà.”+ Àìsáyà 17:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Ọ̀rọ̀ ìkéde sí Damásíkù:+ “Wò ó! Damásíkù ò ní jẹ́ ìlú mọ́,Ó sì máa di àwókù.+
8 Torí Damásíkù ni orí Síríà,Résínì sì ni orí Damásíkù. Kí ọdún márùndínláàádọ́rin (65) tó pé,Éfúrémù máa fọ́ túútúú, wọn ò sì ní jẹ́ èèyàn mọ́.+
4 torí kí ọmọ náà tó mọ bí wọ́n ṣe ń pe, ‘Bàbá mi!’ àti ‘Ìyá mi!’ wọ́n máa kó àwọn ohun àmúṣọrọ̀ Damásíkù àti ẹrù ogun Samáríà lọ níwájú ọba Ásíríà.”+