ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jeremáyà 30:19
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 19 Ìdúpẹ́ àti ohùn ẹ̀rín á ti ọ̀dọ̀ wọn wá.+

      Màá sọ wọ́n di púpọ̀, wọn ò sì ní kéré níye;+

      Màá mú kí wọ́n pọ̀ níye,*

      Wọn ò sì ní jẹ́ ẹni yẹpẹrẹ.+

  • Jeremáyà 31:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  4 Síbẹ̀ náà, màá tún ọ kọ́ bí ilé, wàá sì dà bí ilé tí a tún kọ́.+

      Ìwọ wúńdíá Ísírẹ́lì, wàá tún pa dà mú ìlù tanboríìnì rẹ

      Wàá sì máa jó lọ tayọ̀tayọ̀.*+

  • Jeremáyà 31:27
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 27 “Wò ó! Ọjọ́ ń bọ̀,” ni Jèhófà wí, “tí màá sọ àtọmọdọ́mọ* ilé Ísírẹ́lì àti ilé Júdà di púpọ̀, tí màá sì sọ àwọn ẹran agbéléjẹ̀ wọn di púpọ̀.”+

  • Sekaráyà 2:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 Ó wá sọ fún un pé: “Sáré lọ síbẹ̀ yẹn, kí o sì sọ fún ọkùnrin yẹn pé, ‘“Wọn yóò gbé inú Jerúsálẹ́mù+ bí ìgbèríko gbalasa,* nítorí gbogbo èèyàn àti ẹran ọ̀sìn tó máa wà nínú rẹ̀.”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́