-
Ìsíkíẹ́lì 40:2, 3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 Nínú àwọn ìran tí Ọlọ́run fi hàn mí, ó mú mi wá sí ilẹ̀ Ísírẹ́lì, ó sì gbé mi sórí òkè kan tó ga fíofío.+ Ohun kan wà lórí òkè náà tó dà bí ìlú kan ní apá gúúsù.
3 Nígbà tó mú mi dé ibẹ̀, mo rí ọkùnrin kan tí ìrísí rẹ̀ dà bíi bàbà.+ Ó mú okùn ọ̀gbọ̀ àti ọ̀pá esùsú* tí wọ́n fi ń wọn nǹkan dání,+ ó sì dúró ní ẹnubodè.
-