Ẹ́kísódù 20:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 “Bọlá fún bàbá rẹ àti ìyá rẹ,+ kí ẹ̀mí rẹ lè gùn lórí ilẹ̀ tí Jèhófà Ọlọ́run rẹ máa fún ọ.+ Diutarónómì 5:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 “‘Bọlá fún bàbá rẹ àti ìyá rẹ,+ bí Jèhófà Ọlọ́run rẹ ṣe pa á láṣẹ fún ọ gẹ́lẹ́, kí ẹ̀mí rẹ lè gùn, kí nǹkan sì lè máa lọ dáadáa fún ọ lórí ilẹ̀ tí Jèhófà Ọlọ́run rẹ máa fún ọ.+ Éfésù 6:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 “Bọlá fún bàbá rẹ àti ìyá rẹ,”+ èyí ni àṣẹ kìíní pẹ̀lú ìlérí:
16 “‘Bọlá fún bàbá rẹ àti ìyá rẹ,+ bí Jèhófà Ọlọ́run rẹ ṣe pa á láṣẹ fún ọ gẹ́lẹ́, kí ẹ̀mí rẹ lè gùn, kí nǹkan sì lè máa lọ dáadáa fún ọ lórí ilẹ̀ tí Jèhófà Ọlọ́run rẹ máa fún ọ.+