ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 21:15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 Ṣe ni kí ẹ pa ẹnikẹ́ni tó bá lu bàbá tàbí ìyá rẹ̀.+

  • Léfítíkù 19:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 “‘Kí kálukú yín máa bọ̀wọ̀ fún* ìyá rẹ̀ àti bàbá rẹ̀,+ kí ẹ sì máa pa àwọn sábáàtì+ mi mọ́. Èmi ni Jèhófà Ọlọ́run yín.

  • Diutarónómì 27:16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 “‘Ègún ni fún ẹni tó bá fojú kéré bàbá àti ìyá rẹ̀.’+ (Kí gbogbo èèyàn sì sọ pé, ‘Àmín!’)

  • Òwe 1:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  8 Ọmọ mi, fetí sí ìbáwí bàbá rẹ,+

      Má sì pa ẹ̀kọ́* ìyá rẹ tì.+

  • Máàkù 7:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 Bí àpẹẹrẹ, Mósè sọ pé, ‘Bọlá fún bàbá rẹ àti ìyá rẹ,’+ àti pé, ‘Kí ẹ pa ẹni tó bá sọ̀rọ̀ òdì sí* bàbá tàbí ìyá rẹ̀.’+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́