Mátíù 9:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Wò ó! obìnrin kan tí ìsun ẹ̀jẹ̀+ ti ń yọ lẹ́nu fún ọdún méjìlá (12) sún mọ́ ọn láti ẹ̀yìn, ó sì fọwọ́ kan wajawaja tó wà létí aṣọ àwọ̀lékè rẹ̀,+ Mátíù 9:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Jésù yíjú pa dà, nígbà tó rí i, ó sọ pé: “Mọ́kàn le, ọmọbìnrin! Ìgbàgbọ́ rẹ ti mú ọ lára dá.”+ Láti wákàtí yẹn, ara obìnrin náà yá.+
20 Wò ó! obìnrin kan tí ìsun ẹ̀jẹ̀+ ti ń yọ lẹ́nu fún ọdún méjìlá (12) sún mọ́ ọn láti ẹ̀yìn, ó sì fọwọ́ kan wajawaja tó wà létí aṣọ àwọ̀lékè rẹ̀,+
22 Jésù yíjú pa dà, nígbà tó rí i, ó sọ pé: “Mọ́kàn le, ọmọbìnrin! Ìgbàgbọ́ rẹ ti mú ọ lára dá.”+ Láti wákàtí yẹn, ara obìnrin náà yá.+