-
Mátíù 23:2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 “Àwọn akọ̀wé òfin àti àwọn Farisí ti fi ara wọn sí orí ìjókòó Mósè.
-
-
Máàkù 12:38-40Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
38 Bó ṣe ń kọ́ni, ó sọ pé: “Ẹ ṣọ́ra fún àwọn akọ̀wé òfin tí wọ́n fẹ́ máa rìn kiri nínú aṣọ ńlá, tí wọ́n sì fẹ́ kí wọ́n máa kí wọn níbi ọjà,+ 39 wọ́n fẹ́ ìjókòó iwájú* nínú àwọn sínágọ́gù àti ibi tó lọ́lá jù níbi oúnjẹ alẹ́.+ 40 Wọ́n ń jẹ ilé* àwọn opó run, wọ́n sì ń gba àdúrà tó gùn láti ṣe ojú ayé.* Ìdájọ́ tó le* gan-an ni àwọn yìí máa gbà.”
-