ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 22:7, 8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  7 Gbogbo àwọn tó ń rí mi ló ń fi mí ṣe yẹ̀yẹ́;+

      Wọ́n ń yínmú, wọ́n sì ń mi orí wọn, pé:+

       8 “Ó fi ara rẹ̀ lé Jèhófà lọ́wọ́. Kí Ó gbà á sílẹ̀ báyìí!

      Kí Ó gbà á là, ṣebí ó fẹ́ràn Rẹ̀ gan-an!”+

  • Mátíù 27:42, 43
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 42 “Ó gba àwọn ẹlòmíì là; kò lè gba ara rẹ̀ là! Òun ni Ọba Ísírẹ́lì;+ kó sọ̀ kalẹ̀ báyìí látorí òpó igi oró,* a sì máa gbà á gbọ́. 43 Ó ti gbẹ́kẹ̀ lé Ọlọ́run; kí Ó gbà á sílẹ̀ báyìí tí Ó bá fẹ́ ẹ,+ torí ó sọ pé, ‘Ọmọ Ọlọ́run ni mí.’”+

  • Máàkù 15:31
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 31 Bákan náà, àwọn olórí àlùfáà àti àwọn akọ̀wé òfin ń fi ṣe yẹ̀yẹ́ láàárín ara wọn, wọ́n ń sọ pé: “Ó gba àwọn ẹlòmíì là; kò lè gba ara rẹ̀ là!+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́