Sáàmù 28:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 San ohun tí wọ́n ṣe pa dà fún wọn,+Gẹ́gẹ́ bí iṣẹ́ ibi wọn. San iṣẹ́ ọwọ́ wọn pa dà fún wọn,Gẹ́gẹ́ bí ohun tí wọ́n ṣe.+ Sáàmù 62:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Bákan náà, ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ jẹ́ tìrẹ, Jèhófà,+Nítorí o máa ń san kálukú lẹ́san iṣẹ́ ọwọ́ rẹ̀.+ Òwe 24:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Tí o bá sọ pé: “Ṣebí a ò mọ̀ nípa rẹ̀,”Ṣé Ẹni tó ń ṣàyẹ̀wò ọkàn* kò mọ̀ ni?+ Bẹ́ẹ̀ ni, Ẹni tó ń wò ọ́* máa mọ̀Yóò sì san ẹnì kọ̀ọ̀kan lẹ́san gẹ́gẹ́ bí iṣẹ́ rẹ̀.+
4 San ohun tí wọ́n ṣe pa dà fún wọn,+Gẹ́gẹ́ bí iṣẹ́ ibi wọn. San iṣẹ́ ọwọ́ wọn pa dà fún wọn,Gẹ́gẹ́ bí ohun tí wọ́n ṣe.+
12 Tí o bá sọ pé: “Ṣebí a ò mọ̀ nípa rẹ̀,”Ṣé Ẹni tó ń ṣàyẹ̀wò ọkàn* kò mọ̀ ni?+ Bẹ́ẹ̀ ni, Ẹni tó ń wò ọ́* máa mọ̀Yóò sì san ẹnì kọ̀ọ̀kan lẹ́san gẹ́gẹ́ bí iṣẹ́ rẹ̀.+