Òwe 5:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Nítorí àwọn ọ̀nà èèyàn wà níwájú Jèhófà;Ó ń ṣàyẹ̀wò gbogbo ipa ọ̀nà rẹ̀.+ Òwe 17:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ìkòkò tí wọ́n fi ń yọ́ nǹkan mọ́ wà fún fàdákà, iná ìléru sì wà fún wúrà,+Àmọ́ Jèhófà ni olùṣàyẹ̀wò ọkàn.+ Òwe 21:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Gbogbo ọ̀nà èèyàn máa ń tọ́ lójú ara rẹ̀,+Àmọ́ Jèhófà máa ń ṣàyẹ̀wò ọkàn.*+
3 Ìkòkò tí wọ́n fi ń yọ́ nǹkan mọ́ wà fún fàdákà, iná ìléru sì wà fún wúrà,+Àmọ́ Jèhófà ni olùṣàyẹ̀wò ọkàn.+