1 ÀWỌN ỌBA
OHUN TÓ WÀ NÍNÚ ÌWÉ YÌÍ
-  1  - 
- Dáfídì àti Ábíṣágì (1-4) 
- Ádóníjà wá ọ̀nà láti gorí ìtẹ́ (5-10) 
- Nátánì àti Bátí-ṣébà gbé ìgbésẹ̀ (11-27) 
- Dáfídì pàṣẹ pé kí wọ́n fòróró yan Sólómọ́nì (28-40) 
- Ádóníjà sá lọ sí ibi pẹpẹ (41-53) 
 
-  2  - 
- Dáfídì fún Sólómọ́nì ní ìtọ́ni (1-9) 
- Dáfídì kú; Sólómọ́nì gorí ìtẹ́ (10-12) 
- Ọ̀tẹ̀ Ádóníjà yọrí sí ikú fún un (13-25) 
- Ọba lé Ábíátárì kúrò lẹ́nu iṣẹ́; ó pa Jóábù (26-35) 
- Wọ́n pa Ṣíméì (36-46) 
 
-  3  - 
- Sólómọ́nì fẹ́ ọmọ Fáráò (1-3) 
- Jèhófà fara han Sólómọ́nì lójú àlá (4-15) 
- Sólómọ́nì dá ẹjọ́ láàárín àwọn ìyá méjì (16-28) 
 
-  4  
-  5  
-  6  
-  7  
-  8  - 
- Wọ́n gbé Àpótí wọnú tẹ́ńpìlì (1-13) 
- Sólómọ́nì bá àwọn èèyàn sọ̀rọ̀ (14-21) 
- Àdúrà tí Sólómọ́nì fi ya tẹ́ńpìlì sí mímọ́ (22-53) 
- Sólómọ́nì súre fún àwọn èèyàn náà (54-61) 
- Àwọn ẹbọ àti àjọyọ̀ ìyàsímímọ́ (62-66) 
 
-  9  - 
- Jèhófà tún fara han Sólómọ́nì (1-9) 
- Ẹ̀bùn tí Sólómọ́nì fún Ọba Hírámù (10-14) 
- Oríṣiríṣi iṣẹ́ ìkọ́lé tí Sólómọ́nì ṣe (15-28) 
 
- 10  
- 11  - 
- Àwọn ìyàwó Sólómọ́nì yí i lọ́kàn pa dà (1-13) 
- Àwọn alátakò dìde sí Sólómọ́nì (14-25) 
- Ọlọ́run ṣèlérí ẹ̀yà mẹ́wàá fún Jèróbóámù (26-40) 
- Sólómọ́nì kú; wọ́n fi Rèhóbóámù jọba (41-43) 
 
- 12  - 
- Ìdáhùn líle tí Rèhóbóámù fún àwọn èèyàn (1-15) 
- Ẹ̀yà mẹ́wàá yapa (16-19) 
- Wọ́n fi Jèróbóámù jẹ ọba Ísírẹ́lì (20) 
- Ọlọ́run ní kí Rèhóbóámù má ṣe bá Ísírẹ́lì jà (21-24) 
- Ìjọsìn ère ọmọ màlúù tí Jèróbóámù gbé kalẹ̀ (25-33) 
 
- 13  
- 14  
- 15  - 
- Ábíjámù di ọba Júdà (1-8) 
- Ásà di ọba Júdà (9-24) 
- Nádábù di ọba Ísírẹ́lì (25-32) 
- Bááṣà di ọba Ísírẹ́lì (33, 34) 
 
- 16  - 
- Ìdájọ́ Jèhófà lórí Bááṣà (1-7) 
- Élà di ọba Ísírẹ́lì (8-14) 
- Símírì di ọba Ísírẹ́lì (15-20) 
- Ómírì di ọba Ísírẹ́lì (21-28) 
- Áhábù di ọba Ísírẹ́lì (29-33) 
- Híélì tún Jẹ́ríkò kọ́ (34) 
 
- 17  - 
- Wòlíì Èlíjà sọ tẹ́lẹ̀ pé ọ̀dá máa wà (1) 
- Àwọn ẹyẹ ìwò bọ́ Èlíjà (2-7) 
- Èlíjà dé sọ́dọ̀ opó kan ní Sáréfátì (8-16) 
- Ọmọ opó náà kú, ó sì jíǹde (17-24) 
 
- 18  - 
- Èlíjà pàdé Ọbadáyà àti Áhábù (1-18) 
- Èlíjà àti àwọn wòlíì Báálì ní Kámẹ́lì (19-40) 
- Ọ̀dá ọlọ́dún mẹ́ta àti ààbọ̀ dópin (41-46) 
 
- 19  - 
- Èlíjà sá lọ nítorí ìbínú Jésíbẹ́lì (1-8) 
- Jèhófà fara han Èlíjà ní Hórébù (9-14) 
- Ọlọ́run ní kí Èlíjà fòróró yan Hásáẹ́lì, Jéhù àti Èlíṣà (15-18) 
- Ọlọ́run yan Èlíṣà sí ipò Èlíjà (19-21) 
 
- 20  - 
- Àwọn ará Síríà gbógun ti Áhábù (1-12) 
- Áhábù ṣẹ́gun àwọn ará Síríà (13-34) 
- Àsọtẹ́lẹ̀ lórí Áhábù (35-43) 
 
- 21  - 
- Ọgbà àjàrà Nábótì wọ Áhábù lójú (1-4) 
- Jésíbẹ́lì fa ikú Nábótì (5-16) 
- Iṣẹ́ tí Èlíjà jẹ́ fún Áhábù (17-26) 
- Áhábù rẹ ara rẹ̀ sílẹ̀ (27-29) 
 
- 22  - 
- Àjọṣe Jèhóṣáfátì àti Áhábù (1-12) 
- Mikáyà sọ tẹ́lẹ̀ pé wọ́n máa ṣẹ́gun Áhábù (13-28) 
- Wọ́n pa Áhábù ní Ramoti-gílíádì (29-40) 
- Jèhóṣáfátì ṣàkóso lórí Júdà (41-50) 
- Ahasáyà di ọba Ísírẹ́lì (51-53)