2 ÀWỌN ỌBA
OHUN TÓ WÀ NÍNÚ ÌWÉ YÌÍ
-  1  
-  2  - 
- Ọlọ́run fi ìjì gbé Èlíjà lọ sókè (1-18) 
- Èlíṣà wo omi Jẹ́ríkò sàn (19-22) 
- Àwọn bíárì pa àwọn ọmọdékùnrin tó jáde wá láti Bẹ́tẹ́lì (23-25) 
 
-  3  - 
- Jèhórámù di ọba Ísírẹ́lì (1-3) 
- Móábù ṣọ̀tẹ̀ sí Ísírẹ́lì (4-25) 
- Wọ́n ṣẹ́gun Móábù (26, 27) 
 
-  4  - 
- Èlíṣà sọ òróró opó kan di púpọ̀ (1-7) 
- Obìnrin ará Ṣúnémù ṣe àlejò (8-16) 
- Obìnrin kan rí ọmọ bí; ọmọ náà kú (17-31) 
- Èlíṣà jí ọmọ tó kú dìde (32-37) 
- Èlíṣà mú kí ọbẹ̀ kan ṣeé jẹ (38-41) 
- Èlíṣà sọ búrẹ́dì di púpọ̀ (42-44) 
 
-  5  
-  6  - 
- Èlíṣà mú kí irin àáké léfòó (1-7) 
- Èlíṣà àti àwọn ará Síríà (8-23) - 
- Ojú ìránṣẹ́ Èlíṣà là (16, 17) 
- Ojú inú àwọn ará Síríà fọ́ (18, 19) 
 
- Ìyàn mú ní Samáríà nígbà tí wọ́n dó tì í (24-33) 
 
-  7  - 
- Èlíṣà sọ tẹ́lẹ̀ pé ìyàn máa dópin (1, 2) 
- Wọ́n rí oúnjẹ ní ibùdó tí àwọn ará Síríà ti sá kúrò (3-15) 
- Àsọtẹ́lẹ̀ Èlíṣà ṣẹ (16-20) 
 
-  8  - 
- Wọ́n dá ilẹ̀ obìnrin ará Ṣúnémù pa dà fún un (1-6) 
- Èlíṣà, Bẹni-hádádì àti Hásáẹ́lì (7-15) 
- Jèhórámù di ọba Júdà (16-24) 
- Ahasáyà di ọba Júdà (25-29) 
 
-  9  - 
- Wọ́n fòróró yan Jéhù ṣe ọba lórí Ísírẹ́lì (1-13) 
- Jéhù pa Jèhórámù àti Ahasáyà (14-29) 
- Wọ́n pa Jésíbẹ́lì; àwọn ajá jẹ ẹran ara rẹ̀ (30-37) 
 
- 10  - 
- Jéhù pa agbo ilé Áhábù (1-17) 
- Jéhù pa àwọn olùjọ́sìn Báálì (18-27) 
- Àkópọ̀ ìṣàkóso Jéhù (28-36) 
 
- 11  - 
- Ataláyà fi ipá gba ìtẹ́ (1-3) 
- Wọ́n fi Jèhóáṣì jọba ní bòókẹ́lẹ́ (4-12) 
- Wọ́n pa Ataláyà (13-16) 
- Àwọn àtúnṣe tí Jèhóádà ṣe (17-21) 
 
- 12  - 
- Jèhóáṣì di ọba Júdà (1-3) 
- Jèhóáṣì tún tẹ́ńpìlì ṣe (4-16) 
- Àwọn ará Síríà gbógun wá (17, 18) 
- Wọ́n pa Jèhóáṣì (19-21) 
 
- 13  - 
- Jèhóáhásì di ọba Ísírẹ́lì (1-9) 
- Jèhóáṣì di ọba Ísírẹ́lì (10-13) 
- Èlíṣà dán ìtara Jèhóáṣì wò (14-19) 
- Ikú Èlíṣà; egungun rẹ̀ jí ọkùnrin kan dìde (20, 21) 
- Àsọtẹ́lẹ̀ tí Èlíṣà sọ kẹ́yìn ṣẹ (22-25) 
 
- 14  - 
- Amasááyà di ọba Júdà (1-6) 
- Ó bá Édómù àti Ísírẹ́lì jà (7-14) 
- Ikú Jèhóáṣì ọba Ísírẹ́lì (15, 16) 
- Ikú Amasááyà (17-22) 
- Jèróbóámù Kejì di ọba Ísírẹ́lì (23-29) 
 
- 15  - 
- Asaráyà di ọba Júdà (1-7) 
- Àwọn ọba tó jẹ kẹ́yìn ní Ísírẹ́lì: Sekaráyà (8-12), Ṣálúmù (13-16), Ménáhémù (17-22), Pekaháyà (23-26), Pékà (27-31) 
- Jótámù di ọba Júdà (32-38) 
 
- 16  
- 17  - 
- Hóṣéà di ọba Ísírẹ́lì (1-4) 
- Wọ́n ṣẹ́gun Ísírẹ́lì (5, 6) 
- Ísírẹ́lì lọ sí ìgbèkùn nítorí pé ó di apẹ̀yìndà (7-23) 
- Wọ́n kó àwọn àjèjì wá sí àwọn ìlú Samáríà (24-26) 
- Àwọn ará Samáríà ń ṣe oríṣiríṣi ẹ̀sìn (27-41) 
 
- 18  - 
- Hẹsikáyà di ọba Júdà (1-8) 
- Bí wọ́n ṣe ṣẹ́gun Ísírẹ́lì (9-12) 
- Senakérúbù wá gbéjà ko Júdà (13-18) 
- Rábúṣákè pẹ̀gàn Jèhófà (19-37) 
 
- 19  - 
- Hẹsikáyà wá ìrànlọ́wọ́ Ọlọ́run lọ́dọ̀ Àìsáyà (1-7) 
- Senakérúbù halẹ̀ mọ́ Jerúsálẹ́mù (8-13) 
- Àdúrà Hẹsikáyà (14-19) 
- Àìsáyà sọ ìdáhùn Ọlọ́run fún un (20-34) 
- Áńgẹ́lì pa 185,000 àwọn ará Ásíríà (35-37) 
 
- 20  
- 21  
- 22  - 
- Jòsáyà di ọba Júdà (1, 2) 
- Bí wọ́n ṣe máa tún tẹ́ńpìlì ṣe (3-7) 
- Wọ́n rí ìwé Òfin (8-13) 
- Húlídà sọ tẹ́lẹ̀ pé àjálù máa ṣẹlẹ̀ (14-20) 
 
- 23  - 
- Àwọn àtúnṣe tí Jòsáyà ṣe (1-20) 
- Wọ́n ṣe Ìrékọjá (21-23) 
- Àwọn àtúnṣe míì tí Jòsáyà ṣe (24-27) 
- Ikú Jòsáyà (28-30) 
- Jèhóáhásì di ọba Júdà (31-33) 
- Jèhóákímù di ọba Júdà (34-37) 
 
- 24  - 
- Jèhóákímù ṣọ̀tẹ̀, ó sì kú (1-7) 
- Jèhóákínì di ọba Júdà (8, 9) 
- Ìgbà àkọ́kọ́ tí wọ́n kó wọn lọ sí Bábílónì (10-17) 
- Sedekáyà di ọba Júdà; ó ṣọ̀tẹ̀ (18-20) 
 
- 25  - 
- Nebukadinésárì dó ti Jerúsálẹ́mù (1-7) 
- Ìparun Jerúsálẹ́mù àti tẹ́ńpìlì rẹ̀; wọ́n kó wọn lọ nígbà kejì (8-21) 
- Wọ́n fi Gẹdaláyà ṣe gómìnà (22-24) 
- Wọ́n pa Gẹdaláyà; àwọn èèyàn sá lọ sí Íjíbítì (25, 26) 
- Wọ́n tú Jèhóákínì sílẹ̀ ní Bábílónì (27-30)