2 KÍRÓNÍKÀ
OHUN TÓ WÀ NÍNÚ ÌWÉ YÌÍ
-  1  
-  2  
-  3  
-  4  - 
- Pẹpẹ, Òkun àti àwọn bàsíà (1-6) 
- Ọ̀pá fìtílà, tábìlì àti àgbàlá (7-11a) 
- Bí wọ́n ṣe parí àwọn ohun tó wà nínú tẹ́ńpìlì (11b-22) 
 
-  5  
-  6  
-  7  
-  8  - 
- Àwọn iṣẹ́ ìkọ́lé míì tí Sólómọ́nì ṣe (1-11) 
- Ó ṣètò bí wọ́n á ṣe máa jọ́sìn ní tẹ́ńpìlì (12-16) 
- Àwọn ọkọ̀ òkun Sólómọ́nì (17, 18) 
 
-  9  
- 10  
- 11  
- 12  
- 13  
- 14  
- 15  
- 16  
- 17  - 
- Jèhóṣáfátì di ọba Júdà (1-6) 
- Wọ́n ń kọ́ àwọn èèyàn káàkiri (7-9) 
- Ẹgbẹ́ ológun Jèhóṣáfátì (10-19) 
 
- 18  - 
- Jèhóṣáfátì dara pọ̀ mọ́ Áhábù (1-11) 
- Mikáyà sọ tẹ́lẹ̀ pé wọn ò ní ṣẹ́gun (12-27) 
- Wọ́n pa Áhábù ní Ramoti-gílíádì (28-34) 
 
- 19  
- 20  - 
- Àwọn orílẹ̀-èdè tó yí Júdà ká gbógun tì í (1-4) 
- Jèhóṣáfátì gbàdúrà pé kí Ọlọ́run ran òun lọ́wọ́ (5-13) 
- Ìdáhùn tí Jèhófà fún un (14-19) 
- Ọlọ́run gba Júdà là lọ́nà ìyanu (20-30) 
- Òpin ìjọba Jèhóṣáfátì (31-37) 
 
- 21  - 
- Jèhórámù di ọba Júdà (1-11) 
- Èlíjà kọ̀wé ránṣẹ́ (12-15) 
- Ìgbẹ̀yìn Jèhórámù kò dáa (16-20) 
 
- 22  
- 23  
- 24  
- 25  - 
- Amasááyà di ọba Júdà (1-4) 
- Ogun ja Édómù (5-13) 
- Amasááyà bọ òrìṣà (14-16) 
- Ogun ja Jèhóáṣì ọba Ísírẹ́lì (17-24) 
- Ikú Amasááyà (25-28) 
 
- 26  
- 27  
- 28  - 
- Áhásì di ọba Júdà (1-4) 
- Síríà àti Ísírẹ́lì ṣẹ́gun rẹ̀ (5-8) 
- Ódédì kìlọ̀ fún Ísírẹ́lì (9-15) 
- Ọlọ́run rẹ Júdà wálẹ̀ (16-19) 
- Áhásì bọ̀rìṣà; ikú rẹ̀ (20-27) 
 
- 29  - 
- Hẹsikáyà di ọba Júdà (1, 2) 
- Àwọn àtúnṣe tí Hẹsikáyà ṣe (3-11) 
- Ó fọ tẹ́ńpìlì mọ́ (12-19) 
- Ó mú iṣẹ́ ìsìn tẹ́ńpìlì pa dà sí bó ṣe wà tẹ́lẹ̀ (20-36) 
 
- 30  
- 31  
- 32  - 
- Senakérúbù gbógun ti Jerúsálẹ́mù (1-8) 
- Senakérúbù pẹ̀gàn Jèhófà (9-19) 
- Áńgẹ́lì pa àwọn ọmọ ogun Ásíríà (20-23) 
- Àìsàn tó ṣe Hẹsikáyà àti ìgbéraga rẹ̀ (24-26) 
- Àwọn àṣeyọrí Hẹsikáyà àti ikú rẹ̀ (27-33) 
 
- 33  
- 34  - 
- Jòsáyà di ọba Júdà (1, 2) 
- Àwọn àtúnṣe tí Jòsáyà ṣe (3-13) 
- Wọ́n rí Ìwé Òfin (14-21) 
- Àsọtẹ́lẹ̀ Húlídà nípa àjálù (22-28) 
- Jòsáyà ka ìwé náà fún àwọn èèyàn (29-33) 
 
- 35  
- 36  - 
- Jèhóáhásì di ọba Júdà (1-3) 
- Jèhóákímù di ọba Júdà (4-8) 
- Jèhóákínì di ọba Júdà (9, 10) 
- Sedekáyà di ọba Júdà (11-14) 
- Ìparun Jerúsálẹ́mù (15-21) 
- Àṣẹ tí Kírúsì pa pé kí wọ́n tún tẹ́ńpìlì kọ́ (22, 23)