Ojú ìwé 2
Àwọn Àrùn Panipani Ogun Tí Ènìyàn Ń Bá Kòkòrò Àrùn Jà 3-11
Ibo ni àwọn àrùn wọ̀nyí ti ń wá? Èé ṣe tí ó fi dà bí ẹni pé àwọn kòkòrò àrùn ń rọ́wọ́ mú? Ojútùú kan ha wà bí?
Etiopia Fífani Mọ́ra 16
Kọ́ nípa ìtàn ìfanimọ́ra, onírúurú ènìyàn, ìrísí ilẹ̀ tí ó ṣàrà ọ̀tọ̀, àti àwọn ẹranko Etiopia.
Ọ̀rẹ́ Mi Ọ̀wọ́n 26
Kà nípa ọ̀rẹ́ tímọ́tímọ́ èwe kan—obìnrin kan tí ó fi nǹkan bí ẹ̀wádún méje jù ú lọ.
[Àwòrán Credit Line tó wà ní ojú ìwé 2]
Fáírọ́ọ̀sì lókè ojú ewé 2, 3, 4, àti 10: Ibùdó CDC, Atlanta, Ga.