Ojú ìwé 2
Òmìnira Ọ̀rọ̀ Sísọ—A Ha Ń Ṣì Í Lò Bí? 3-11
A ti ṣe àwọn òfin, a ti ja àwọn ogun, àwọn ẹ̀mí sì ti sọnù nínú ìjàkadì láti fìdí ẹ̀tọ́ òmìnira ọ̀rọ̀ sísọ múlẹ̀. Ní báyìí, àwọn ohùn tuntun ń ké gbàjarè pé kí a fawọ́ àwọn òfin tí ó lòdì sí àṣìlò òmìnira ọ̀rọ̀ sísọ sẹ́yìn.
Ìdí Tí Ó Fi Yí Ohun Àkọ́múṣe Rẹ̀ Padà 15
Ka ìtàn fífàfẹ́ mọ́ra nípa olùtọ́jú ọgbà tẹ́lẹ̀ rí kan ní Minsmere, igbó ọba kan tí ó jẹ́ 800 hẹ́kítà ní England. Ó fi ipò rẹ̀ sílẹ̀ nítorí iṣẹ́ àyànfúnni mìíràn. Èé ṣe?
Èé Ṣe Tí Àwọn Ọ̀dọ́ Mìíràn Ń Gbádùn Gbogbo Ìmóríyá Náà? 25
Jason ọmọ ọdún 15 kan ṣàròyé pé: “A wulẹ̀ fẹ́ láti ní ìmóríyá ni, kò rọrùn rárá.”