Ojú ìwé 2
Ṣíṣètọ́jú Kíkojú Ìpèníjà Náà 3-13
Bí iye àwọn arúgbó ti ń pọ̀ sí i nílùú, tí ó sì jẹ́ òtítọ́ pé àìsàn líle koko lè kọ lù wọ́n ní ọjọ́ orí èyíkéyìí, àwọn ìdílé lónìí ń kojú ìpinnu tí ó lágbára nípa ìtọ́jú àwọn ìbátan wọn. Ìrànlọ́wọ́ wo ni a lè ṣe fún àwọn tí ń ṣètọ́jú?
Gbin Àwọn Èèhù Tìrẹ Fúnra Rẹ 23
Nípa lílo ìwọ̀nba àkókò àti ìsapá, o lè gbin àwọn èèhù ní ilé rẹ.
Ìkún Omi Náà—Òtítọ́ Tàbí Àròsọ? 26
Kí ni ẹ̀rí tí ó dájú jù lọ pé Ìkún Omi ọjọ́ Nóà jẹ́ òtítọ́? Ka ojú ìwòye Bíbélì.
[Àwòrán Credit Line tó wà ní ojú ìwé 2]
Nóà: L. Chapons/Illustrirte Familien-Bibel nach der deutschen Uebersetzung Dr. Martin Luthers