Ojú ìwé 2
Ìwà Ọ̀daràn Tí Ẹgbẹ́ Ń Ṣètò Bí Ó Ṣe Ń Nípa Lórí Rẹ 3-10
Ìwà ọ̀daràn tí kò mọ sí orílẹ̀-èdè kan ń nípa lórí ẹni gbogbo. Gbogbo nǹkan ló gbówó lórí—láti orí ìkólẹ̀kóràwé dé orí ohun ọ̀ṣọ́, láti orí aṣọ dé orí sìmẹ́ǹtì. Àwọn ọ̀daràn ń dúnkookò mọ́ àwọn adájọ́, ọlọ́pàá, àti òṣèlú, wọ́n sì ń bà wọ́n níwà jẹ́. Ojútùú kankan ha wà bí?
Àwọn Òdòdó Ń Fi Hàn Pé Ẹnì Kan Bìkítà 16
Ìgbà wo ni o ti ra òdòdó kan fún olólùfẹ́ kan gbẹ̀yìn? Ìsapá wo ló ń mú àwọn òdòdó wọ̀nyẹn jáde? Ibo ni wọ́n ti ń wá?
Ó Ha Yẹ Kí Àwọn Ọmọdé Yan Ìsìn Tiwọn Bí? 26
Àwọn òbí kan rò pé kò yẹ kí a fi ìsìn kọ́ àwọn ọmọdé, ṣùgbọ́n pé ó yẹ kí wọ́n yàn fúnra wọn nígbà tó bá yá. Kí ni Bíbélì wí?
[Credit Line tó wà ní ojú ìwé 2]
Àwòrán ilẹ̀: Mountain High Maps® Copyright © 1995 Digital Wisdom, Inc.
[Àwòrán Credit Line tó wà ní ojú ìwé 2]
The Doré Bible Illustrations/Dover Publications, Inc.