Ojú ìwé 2
Ìsìn Ń Jagun Ọlọ́run Ha Fọwọ́ Sí I Bí? 3-11
Jálẹ̀jálẹ̀ ìtàn, àwọn ènìyàn ti pànìyàn lórúkọ Ọlọ́run. A ha lè dá àre fún irú ìpànìyàn bẹ́ẹ̀ bí? Ojú wo ni Ọlọ́run fi wò ó?
Ìrètí Fífẹsẹ̀múlẹ̀ Láàárín Ipò Ìbànújẹ́ ní Chernobyl 12
Yeltsin, Ààrẹ ilẹ̀ Rọ́ṣíà, sọ pé: “Aráyé kò tí ì rí irú àjálù tí ó pọ̀ tó báyìí rí.”
Nísinsìnyí, Mo Láyọ̀ Láti Wà Láàyè! 20
Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé Ginger ti fìgbà kan dàníyàn láti kú—ó tilẹ̀ gbìyànjú láti pa ara rẹ̀—ó láyọ̀ láti wà láàyè nísinsìnyí. Mọ̀ nípa ohun tó fà á.
[Àwòrán Credit Line tó wà ní ojú ìwé 2]
Bibliothèque Nationale, Paris
[Àwòrán Credit Line tó wà ní ojú ìwé 2]
Tass/Sipa Press
[Àwòrán Credit Line tó wà ní ojú ìwé 2]
Ẹ̀yìn ìwé: Alexandra Boulat/Sipa Press