Ojú ìwé 2
Báwo La Ṣe Déhìn-ín? Nípasẹ̀ Èèṣì Ni Tàbí Nípasẹ̀ Àpilẹ̀ṣe? 3-17
Darwin kò mọ̀ nípa àwọn àléébù tí ìmọ̀ nípa molecule nínú ẹ̀kọ́ nípa ohun alààyè yóò tú fó nínú àbá èrò orí tí ó gbé kalẹ̀. Ìbéèrè náà síbẹ̀ ni pé, Ṣé nípasẹ̀ èèṣì la fi déhìn-ín ni tàbí nípasẹ̀ àpilẹ̀ṣe?
Gbígbẹ́jọ́ “Aládàámọ̀” Kan àti Pípa Á 18
Ìwádìí tí Kátólíìkì ṣe Láti Gbógun Ti Àdámọ̀ fa ikú ẹgbẹẹgbẹ̀rún ènìyàn. Èé ṣe tí ṣọ́ọ̀ṣì fi gbọ̀jẹ̀gẹ́ fún ìwà ipá yìí?
Tasmania—Erékùṣù Kékeré, Onítàn Àrà Ọ̀tọ̀ 24
Èé ṣe tí Tasmania di àgbègbè ìfìyàjẹni ìgbókèèrè-ṣàkóso ilẹ̀ Britain? Báwo ni àwọn ará Britain ṣe hùwà sí àwọn Aborigine náà? Báwo ni ìgbésí ayé ṣe rí ní Tasmania òde òní?
[Àwòrán Credit Line tó wà ní ojú ìwé 2]
The Complete Encyclopedia of Illustration/J. G. Heck