Ojú ìwé 2
Ìsokọ́ra Alátagbà Internet Ó Ha Wà fún Ọ Bí? 3-13
Ó jẹ́ ẹnubodè àbáwọlé sí àyíká orísun ìsọfúnni tí ó jọ pé kò ṣeé lò tán. Àwọn kan sọ pé, ó jẹ́ ọ̀nà márosẹ̀ ìfìsọfúnni-ránṣẹ́. Ìwọ bí ẹnì kan ha nílò rẹ̀ bí? Àwọn ìdí kan ha wà tí a fi ní láti ṣọ́ra bí?
Èé Ṣe Tí Ó Fi Ń Jẹ́ Ẹ̀bi Mi Nígbà Gbogbo? 18
Ó ha máa ń jọ pé ìwọ ni a máa ń dá lẹ́bi fún ohunkóhun tó bá ṣàìtọ́? Báwo ni o ṣe lè kojú ìṣelámèyítọ́ tí kò tọ́?
Ọ̀nà Ìgbésí Ayé Eléwu—Báwo Ni Ohun Tí Ń Náni Ṣe Pọ̀ Tó? 24
A ń gba ọ̀pọ̀ ènìyàn sílé ìwòsàn nítorí àwọn àrùn àti ìpalára tí wọn ì bá ti yẹra fún. Kí ni okùnfà rẹ̀? Ọ̀nà ìgbésí ayé eléwu.