Ojú ìwé 2
Ran Àwọn Ọmọ Rẹ Lọ́wọ́ Láti Ní Láárí 3-11
Kí àwọn ọmọ lè níláárí, wọ́n nílò àyíká tí ń pèsè ìmọ̀lára gbígbámúṣé. Báwo ni àwọn òbí ṣe lè pèsè èyí?
Oúnjẹ fún Gbogbo Ènìyàn—Àlá Lásán Ni Bí? 12
A ha lè bọ́ iye ènìyàn tí ń pọ̀ sí i lórí ilẹ̀ ayé bó ti yẹ nígbà tí ọ̀pọ̀ ènìyàn jẹ́ arebipa nísinsìnyí bí?
Àwọn Kíndìnrín Rẹ—Asẹ́ Ìgbẹ́mìíró 24
Báwo ni àwọn kíndìnrín rẹ ṣe ń ṣiṣẹ́? Àpilẹ̀kọ fífani-lọ́kànmọ́ra yìí yóò sọ fún ọ.
[Àwòrán Credit Line tó wà ní ojú ìwé 2]
Dorothea Lange, FSA Collection, Library of Congress