Ojú ìwé 2
Ohun Tí Ogun Ń ṣe Fún Àwọn Ọmọdé 3-11
Kí ló dé tí a ń fi àwọn ọmọdé ṣe sójà? Báwo ni ogun ṣe ń ṣe wọ́n níṣekúṣe? Síbẹ̀, èé ṣe tí a fi lè ní ìdánilójú ọjọ́ ọ̀la amọ́kànyọ̀ fún àwọn ọmọdé òde òní?
Ẹ̀kọ́ Àríkọ́gbọ́n Láti Inú Ìkòkò Ọ̀rá Kan 20
Ìtàn tí ń fún ìgbàgbọ́ lókun nípa Kurt Hahn tẹnu mọ́ ẹ̀kọ́ àríkọ́gbọ́n ṣíṣeyebíye kan tí a lè rí kọ́ láti inú ìkòkò ọ̀rá kan.
Èé Ṣe Tí Wọ́n Ń Fún Arákùnrin Mi Ní Gbogbo Àfiyèsí? 25
Kí ló yẹ kí o ṣe bí ó bá jọ pé àwọn òbí rẹ ń ṣe ojúsàájú fún ọ̀kan lára àwọn ọmọ ìyá rẹ?
[Àwòrán Credit Line tó wà ní ojú ìwé 2]
Nanzer/Sipa Press
[Àwòrán Credit Line tó wà ní ojú ìwé 2]
Ojú ewé 1, 3, 4, àti 7: Fọ́tò U.S. Navy