Ojú ìwé 2
Ariwo Òun Ló Ń Ṣèdíwọ́ fún Wa Jù Bí? 3-11
Ó ha ṣòro fún ọ láti yẹra fún ariwo tí kò dẹwọ́ bí? Ariwo ha ń ni ọ́ lára bí? O jẹ́ ọ̀kan lára ọ̀pọ̀ bílíọ̀nù ènìyàn tí aṣèdíwọ́ òde òní yìí ń dá lóró. Báwo ni o ṣe lè rí ìtura?
Ọkùnrin Tó Ṣí Ayé Payá 12
Gbogbo ènìyàn ti gbọ́ nípa Columbus. Ṣùgbọ́n ta ni arìnrìn-àjò ojú òkun tó kọ́kọ́ rìn yí àgbáyé po? Onígboyà olùṣàwárí ọmọ ilẹ̀ Potogí kan ni. Àwọn ìdánwò wo ló dojú kọ? Báwo ló ṣe kú?
Ipò Òṣì Ha Dá Olè Jíjà Láre Bí? 18
Àwọn kan ronú pé àwọn ni láti jalè kí àwọn lè kojú ipò òṣì. Bíbélì ha fàyè gba èrò yẹn bí?
[Àwòrán Credit Line tó wà ní ojú ìwé 2]
Robin Hood: General Research Division/The New York Public Library/Astor, Lenox and Tilden Foundations