Ojú ìwé 2
Àbójútó Ọmọ Kí Ni Èrò Oníwọ̀ntúnwọ̀nsì? 3-12
Nígbà tí àwọn òbí bá kọ ara wọn sílẹ̀, báwo ni a ṣe ń pinnu bí a ó ṣe bójú tó àwọn ọmọ wọn? Ta ní ń pinnu ohun tí ìdánilẹ́kọ̀ọ́ wọn nípa ìsìn lọ́jọ́ iwájú yóò jẹ́?
Ó Ha Yẹ Kí Àwọn Kristẹni Kórìíra Àwọn Abẹ́yà-Kannáà-Lòpọ̀? 13
Kí Ni Ojú Ìwòye Bíbélì?
Àwọn Kúrékùré—Àwọn Olùgbé Inú Igbó Jìndunjìndun 20
Ta ni wọ́n? Báwo ni ìgbésí ayé wọn ṣe rí?
[Àwòrán Credit Line tó wà ní ojú ìwé 2]
Punch