Ojú ìwé 2
Ẹgbẹ́ Ọmọ Ìta Ìṣòro Tí Ń Pọ̀ sí I Jákèjádò Ayé 3-11
Èé ṣe tí àwọn ọ̀dọ́ púpọ̀ tó bẹ́ẹ̀ ń wọ ẹgbẹ́ ọmọ ìta? Kí ló dé tí ó fi ṣòro gan-an láti kúrò nínú ẹgbẹ́ ọmọ ìta kan? Báwo ni o ṣe lè dáàbò bo àwọn ọmọ rẹ lọ́wọ́ wọn?
Àwọn Ìwé Kíkéréjù Tí Ó Wuni 13
Báwo ni àwọn ìwé wọ̀nyí ṣe kéré tó? Èé ṣe tí wọ́n fi kéré tó bẹ́ẹ̀? Báwo ni wọ́n ti ṣe wúlò gan-an fún àwọn Kristẹni?
Ìsapá Wa Lórí Ẹ̀tọ́ Láti Wàásù 20
Grace Marsh jagun mólú ní Ilé Ẹjọ́ Gígajùlọ ní United States, èyí ṣèrànwọ́ láti fìdí òmìnira ìsìn múlẹ̀. Kà nípa ìtàn ìgbésí ayé rẹ̀ tí ó gbádùn mọ́ni.
[Àwòrán Credit Line tó wà ní ojú ìwé 2]
Nípasẹ̀ ìyọ̀ǹda onínúure British Library