Ojú ìwé 2
Ǹjẹ́ A Lè Dáàbò Bo Àwọn Igbó Kìjikìji Wa? 3-13
Wọ́n ń piyẹ́ àwọn igbó kìjikìji àgbáyé, búrùjí ẹlẹgẹ́ tó sì ṣe pàtàkì kan. Ọ̀pọ̀ ènìyàn rí èyí bí ewu kan fún àjọṣepọ̀ àwọn ohun alààyè àti àyíká wọn lórí ilẹ̀ ayé àti fún ìwàláàyè aráyé. Ǹjẹ́ ojútùú kan wà?
Ìrìn Àjò Ọlọ́jọ́ Gbọọrọ Mi Láti Inú Ìwàláàyè àti Ikú ní Cambodia 16
Wathana Meas jẹ́ ọkùnrin ajẹ́jẹ̀ẹ́ ànìkàngbé ẹlẹ́sìn Búdà kan tẹ́lẹ̀, ó wá di ọmọ ogun kan nínú ẹgbẹ́ ogun ilẹ̀ Cambodia. Ìtàn ìgbésí ayé rẹ̀ jẹ́ ìrìnkiri wíwọnilọ́kàn ti lílàájá.
Báwo Ni Ọdún 2000 Ti Ṣe Pàtàkì Tó? 20
Ǹjẹ́ Bíbélì tọ́ka sí ọdún 2000? Ṣé ó yẹ kí àwọn Kristẹni máa ṣàníyàn nípa déètì yẹn?