Ojú ìwé 2
Báwo Ni Ìgbésí Ayé Ṣe Lè Ní Ààbò Pípẹ́ Títí? 3-10
Àràádọ́ta ọ̀kẹ́ ènìyàn ń róye pé ìgbésí ayé àwọn àti ọ̀nà tí àwọn ń gbà gbé e ń wà nínú ewu, kò sì láyọ̀lé. Ǹjẹ́ a tilẹ̀ lè retí láti gbé ìgbésí ayé tí ó ní ààbò pípẹ́ títí bí? Bẹ́ẹ̀ ni, ààbò ń bẹ lọ́jọ́ iwájú!
Ìsìn ní Poland Òde Òní 15
Kí ni ìṣarasíhùwà ọ̀pọ̀ ènìyàn nípa Ìjọ Kátólíìkì ní Poland?
Ìjẹ́pàtàkì Dídáwà 18
Kí ni èrò Bíbélì nípa àwọn àǹfààní dídáwà àti àbùkù rẹ̀?