Ojú ìwé 2
Orin—Ó Lágbára Ju Bóo Ti Rò Lọ 3-10
Agbára wo lorin lè ní lórí wa? Ohun wo ló yẹ ká ṣọ́ra fún nígbà tí a bá fẹ́ yan ohun tí a óò gbọ́?
Bí A Ṣe Lè Yan Ẹni Tí A Óò Fẹ́ 20
Kí ni Bíbélì sọ nípa ọ̀ràn yìí?
Dáàbò Bo Ọmọ Rẹ Kí Jàǹbá Má Bàa Ṣe É 22
Báwo la ṣe lè ṣe é tí jàǹbá ò fi ní máa ṣẹlẹ̀ sí àwọn ọmọdé tó bẹ́ẹ̀ mọ́? Kí la lè ṣe tó bá tiẹ̀ wá di pé jàǹbá ṣẹlẹ̀ sí wọn?
[Àwòrán Credit Line tó wà ní ojú ìwé 2]
IWÁJÚ ÌWÉ: Fọ́tò ọkùnrin tó ń fun fèrè alápò awọ: Garo Nalbandian