Atọ́ka Ìdìpọ̀ Ọgọ́rin ti Jí!
ÀJỌṢE Ẹ̀DÁ
Àwọn Òbí Àgbà, 4/8
Bí Ẹnì Kejì Wa Nínú Ìgbéyàwó Bá Hùwà Àìṣòótọ́, 5/8
Fi Hàn Pé O Bìkítà (àwọn arúgbó), 4/8
Ìtàn Bíbaninínújẹ́ Nípa Òwò Ẹrú, 3/8
Lẹ́tà sí Àwọn Òbí Wọn (Sípéènì), 7/8
Yíyan Ẹni Tí A Óò Fẹ́, 10/8
ÀWỌN ẸLẸ́RÌÍ JÈHÓFÀ
Àwọn Irúgbìn Tó Sèso Lẹ́yìn Ọ̀pọ̀ Ọdún, 7/8
Àwọn Obìnrin Ṣe Bẹbẹ (Zimbabwe), 7/8
‘Báwo Ni Iṣẹ́ Yín Ṣe Ń Ṣe Àwùjọ Láǹfààní Tó?’ 6/8
Dídúró Gbọn-in Nígbà Ìṣàkóso Násì (Netherlands), 11/8
Ìgbàgbọ́ Ọmọkùnrin Náà Fún Ọmọbìnrin Yìí Lókun, 11/8
Inú Jí! Ló Ti Rí Àwòrán Ìpolongo Ìlòdìsí Sìgá Mímu, 7/8
Kò Juwọ́ Sílẹ̀, 1/8
Lẹ́tà Sáwọn Òbí Wọn (Sípéènì), 7/8
Lẹ́yìn Ìjì (Mòsáńbíìkì), 7/8
Nígbà Tí Òjò Bá Kọ̀ Tí Kò Rọ̀ (Brazil), 9/8
Ọlọ́run Ló Ń Ràn Wá Lọ́wọ́ (Mòsáńbíìkì), 7/8
Wọ́n Pinnu Láti Má Ṣe Juwọ́ Sílẹ̀, 9/8
ÀWỌN ẸRANKO ÀTI OHUN Ọ̀GBÌN
Ajá Mi Ló Ń Gbọ́rọ̀ fún Mi! 8/8
Ẹja Tí Ń Rìn (atọkúṣọ́-nínú-ẹrọ̀fọ̀), 11/8
Igi Tí Ń Kọrin, 7/8
Kẹ́míkà Apakòkòrò Jewéjewé, 5/8
Kìnnìún, 2/8
Ọ̀pẹ, 3/8
ÀWỌN Ọ̀DỌ́ BÉÈRÈ PÉ
Báwo Ni Mo Ṣe Lè Ṣàṣeyọrí Láìsí Àwọn Òbí Mi? 1/8
Èé Ṣe Tí Èrò Bí Mo Ṣe Tóbi Tó Fi Gbà Mí Lọ́kàn? 5/8
Fífarada Ìwà Àìdáa, 10/8
Fífẹ́ Ẹni Tí Ọ̀nà Rẹ̀ Jìn, 2/8
Gbígbé Ọ̀ràn Sísanra Sọ́kàn, 6/8
Kí Ló Dé Tí Mọ́mì Fi Ń Ṣàìsàn Tó Bẹ́ẹ̀? 8/8
Kí Ló Dé Tí N Kò Lè Ní Àwọn Ohun Tí Mo Ń Fẹ́? 4/8
Òfófó, 3/8
Títúraká, 11/8, 12/8
Wọ́n Ń Ṣáátá Mi, 7/8
ÀWỌN Ọ̀RÀN ÀTI IPÒ AYÉ
Àwọn Ọmọdé Wà Nínú Ewu, 4/8
Ètò Tí Àjọ UN Ṣe Nítorí Àwọn Ọ̀dọ́, 1/8
Ewu Ogun Ọ̀gbálẹ̀gbáràwé, 9/8
Ẹ̀tọ́ Ha Lè Wà Láìsí Ojúṣe Bí? (àjọ UN), 1/8
‘Gbogbo Èèyàn Kọ́ Ló Ń Jẹ Nínú Àǹfààní Náà’ (ohun àlùmọ́nì ilẹ̀ ayé), 8/8
Kíkó Ọmọdé Ṣiṣẹ́, 6/8
Ogun Yóò Ha Dópin Láé Bí? 10/8
Ọ̀rúndún Ogún—Àwọn Ọdún Ìyípadà Pípeléke, 12/8
ÌLERA ÀTI ÌṢÈGÙN
Àbójútó Èrò Orí, 2/8, 7/8
A Kọ́ Láti Gbẹ́kẹ̀ Lé Ọlọ́run (ọmọ tí oṣù ẹ̀ ò pé), 12/8
Àwọn Ọmọdé àti Jàǹbá, 10/8
Báwo Ló Ṣe Yẹ Kí Ọmọ Ọwọ́ Máa Sùn? 6/8
Bíbá Ikọ́ Ẹ̀gbẹ Jà, 6/8
Bí O Ṣe Ń Gbé Ìgbésí Ayé Rẹ Ha Ń Pa Ẹ́ Lọ Bí? 7/8
Dáàbò Bo Ara Rẹ Lọ́wọ́ Kòkòrò Àfòmọ́! 6/8
Ipa Tí Àyíká Ń Ní Lórí Ìlera, 11/8
Ǹjẹ́ Ìfàjẹ̀sínilára Tiẹ̀ Pọndandan? 9/8
Ó Ti Sunwọ̀n Sí I Jákèjádò Ayé—Àmọ́ Gbogbo Èèyàn Kọ́ Ló Ń Jàǹfààní Rẹ̀, 10/8
Ọ̀ràn Ìbànújẹ́ Kárí Ayé (ikú aboyún), 5/8
Pẹ́ Láyé Kí Ara Rẹ Sì Tún Le Dáadáa, 8/8
ILẸ̀ ÀTI ÀWỌN ÈNÌYÀN
Ẹ̀pà Lílọ̀—Bí Wọ́n Ṣe Ń Ṣe É ní Áfíríkà, 9/8
Ẹyọ Owó ní Áfíríkà (ẹyọ owó àwọn Kissi), 6/8
Ilà Ẹ̀rẹ̀kẹ́—‘Àmì Ìdánimọ̀’ ní Nàìjíríà, 1/8
Ìtàn Bíbaninínújẹ́ Nípa Òwò Ẹrú (Senegal), 3/8
Nígbà Tí Òjò Bá Kọ̀ Tí Kò Rọ̀ (Brazil), 11/8
ÌSÌN
Àwọn Àmẹ́ríńdíà àti Bíbélì, 5/8
Ìsìn Ń Wọ̀ọ̀kùn ní Ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì, 9/8
Olùlàjà Ni Wọ́n Àbí Adógunsílẹ̀? 3/8
Òmìnira Rẹ̀ Wà Nínú Ewu, 1/8
Ọlọ́run Ha Wà Bí? 2/8
Sísọ̀rọ̀ Nípa Ìsìn, 3/8
Ṣé Àyànmọ́ Ló Ń Darí Ayé Rẹ? 8/8
ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ
Àádọ́ta Ọdún Lábẹ́ Ìgbonimọ́lẹ̀ (L. Toom), 3/8
Bí Mo Tilẹ̀ Fọ́jú, Mo Wúlò, Mo Sì Láyọ̀ (P. Venetsianos), 3/8
Ẹni Bíi Kìnnìún Abúramúramù Di Àgùntàn Onínú Tútù (E. Torres), 9/8
Mo Dúpẹ́ Lọ́wọ́ Jèhófà Nítorí Àwọn Ọmọkùnrin Mi Márààrún (H. Saulsbery), 4/8
Ọlọ́run Ló Ń Ràn Wá Lọ́wọ́ (F. Coana), 7/8
Sísin Ọlọ́run ní Bèbè Ikú (J. Mancoca), 9/8
Títọ́mọ ní Áfíríkà (C. McLuckie), 11/8
Títọ́ Ọmọkùnrin Méje (B. & M. Dickman), 2/8
Wọ́n Lé Wa Kúrò Nílùú Lọ sí Siberia! (V. Kalin), 5/8
OJÚ ÌWÒYE BÍBÉLÌ
Ìṣọ̀kan Ìjọsìn Nínú Ìgbéyàwó, 8/8
Kí Ló Fà Á Táwọn Kan Fi Ń Ṣàjẹ́? 11/8
Kí Ni Ẹ̀mí Mímọ́ Ọlọ́run? 1/8
Kí Ni Ojúṣe Ẹni Rere Nílùú? 9/8
Ǹjẹ́ Àwọn Ọba Mẹ́ta Bẹ Jésù Wò ní Bẹ́tílẹ́hẹ́mù? 12/8
Ǹjẹ́ Ó Lòdì Láti Yangàn? 7/8
Ó Ha Lòdì Láti Máa Pe Orúkọ Ọlọ́run Bí? 3/8
Ó Ha Yẹ Kí A Bọlá fún Òkú Bí? 2/8
O Ṣeyebíye Lójú Ọlọ́run! 6/8
Yíyan Ẹni Tí A Óò Fẹ́, 10/8
Yíyáni Lówó àti Yíyáwó, 4/8
Ọ̀KANKÒJỌ̀KAN
Áńgẹ́lì, 12/8
Aṣọ Ìsìnkú Jésù Kẹ̀? 1/8
Ìgbàgbọ́ Nínú Ohun Asán, 11/8
Ìjẹ́mímọ́ Kristẹni, 7/8
Ilé Rẹ Ha Wà Láìséwu Bí? 12/8
Irú Aṣọ Tí A Ń Wọ̀, 2/8
Ǹjẹ́ O Mọ̀, 2/8, 4/8, 6/8, 8/8, 10/8
Orin, 10/8
Ọgbọ́n àti Àǹfààní Ṣíṣètò Dúkìá Ẹni, 1/8