Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
March 8, 2001
Kí Ló Yẹ Ká Kọ́ Nínú Àwọn Ohun Tó Ti Ṣẹlẹ̀ Kọjá?
Ṣé àǹfààní kankan tiẹ̀ wà nínú mímọ̀ nípa àwọn ohun tó ti ṣẹlẹ̀ kọjá? Kí la lè rí kọ́ nínú wọn? Ǹjẹ́ ohun tó wà nínú Bíbélì tiẹ̀ wúlò lónìí?
3 Àwọn Ohun Tó Ti Ṣẹlẹ̀ Kọjá—Ǹjẹ́ ó Yẹ Ká Gbà Wọ́n Gbọ́?
4 Kí La Lè Rí Kọ́ Látinú Ohun Tó Ti Ṣẹlẹ̀ Kọjá?
8 Bíbélì—Ṣó Yẹ Ká Gba Àwọn Ìtàn Inú Rẹ̀ Gbọ́?
11 Ìgbádun Tó Wà Nínú Wíwo Ẹyẹ
14 ‘Wọn Yóò Fi Idà Wọn Rọ Abẹ Ohun Ìtúlẹ̀’—Nígbà Wo?
20 Ogun Náà Ò Dáṣẹ́ Ìwàásù Wa Dúró
25 Ẹ̀kọ́ Táwọn Èèyàn Kọ́ Látinú Ohun Tó Ṣẹlẹ̀ sí Loida
30 Wíwo Ayé
Ìṣirò Nípa Àrùn Éèdì Ń Kóbànújẹ́ Ńláǹlà Báni! 12
Àwọn tó ti lùgbàdì àrùn éèdì lé ní mílíọ̀nù mẹ́rìnlélọ́gbọ̀n. Àwọn ohun wo ló ń mú kó gbèèràn bẹ́ẹ̀?
Ipa tí ọkọ̀ òkun alájẹ̀ ti ọ̀rúndún kẹtàdínlógún kó nínú ìtàn ilẹ̀ Faransé jẹ́ ìtàn tó ní í ṣe pẹ̀lú ìgbéraga àti fífìyà jẹ ọmọnìyàn.
[Àwọn àwòrán Credit Line tó wà ní ojú ìwé 2]
Àwòrán àárín lẹ́yìn ìwé: Ibi ìkówèésí Franklin D. Roosevelt
Fọ́tò: Brett Eloff