Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
October–December 2008
Ṣé Ikú Lòpin Ohun Gbogbo?
Ka àwọn àlàyé tó fi hàn pé ikú kọ́ lòpin ohun gbogbo. Á tún dáa kó o kíyè sí ohun tó máa mú kó ṣeé ṣe àti ohun tí Bíbélì sọ nípa bí ayé ṣe máa rí nígbà yẹn.
3 Ṣóòótọ́ Ni Pé Ikú Lòpin Ohun Gbogbo?
4 Ṣé Ẹní Bá Ti Kú Lè Pa Dà Wà Láàyè?
7 Ìwàláàyè Nínú Párádísè Tí Ọlọ́run Ṣèlérí
11 “Ẹ Ṣeun Púpọ̀ fún Ìfẹ́ Àtọkànwá Tẹ́ Ẹ Ní Sáwọn Èèyàn”
31 Ìwé Ìròyìn Jí! Ràn Mí Lọ́wọ́ Láìròtẹ́lẹ̀
32 “Mi Ò Mọ̀ Pé Ọlọ́run Lórúkọ”
Ṣó Yẹ Ká Máa Fi Ère Jọ́sìn Ọlọ́run? 12
Ọ̀kẹ́ àìmọye èèyàn ló ń fi ère àtàwọn nǹkan míì jọ́sìn Ọlọ́run. Ojú wo ni Ẹlẹ́dàá fi ń wo àṣà yìí?
Báwo Ni Mo Ṣe Lè Kojú Wàhálà Níléèwé? 21
Kà nípa ọ̀pọ̀ nǹkan tó sábà máa ń mú káwọn ọ̀dọ́ fojú winá wàhálà níléèwé àtàwọn nǹkan tí wọ́n lè ṣe sí i.