Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
APÁ 1—ÌGBÀ ÌṢẸ̀DÁ SÍ ÌGBÀ ÌKÚN-OMI
1 Ọlọ́run Bẹ̀rẹ̀ sí Í Ṣẹ̀dá Àwọn Nǹkan
4 Ìdí Tí Wọ́n Fi Pàdánù Ibùgbé Wọn
10 Ìkún-Omi Ńlá
APÁ 2—LÁTI ÌGBÀ ÌKÚN-OMI TÍTÍ DÉ ÌGBÀ ÌDÁǸDÈ KÚRÒ NÍ ÍJÍBÍTÌ
14 Ọlọ́run Dán Ìgbàgbọ́ Ábúráhámù Wò
21 Àwọn Ẹ̀gbọ́n Jósẹ́fu Kórìíra Rẹ̀
24 Jósẹ́fù Dán Àwọn Ẹ̀gbọ́n Rẹ̀ Wò
26 Jóòbù Jẹ́ Olóòótọ́ sí Ọlọ́run
27 Ọba Búburú Kan Jẹ ní Íjíbítì
28 Bá A Ṣe Gba Mósè Ọmọ Ọwọ́ Là
30 Igbó Tí Ń Jó
31 Mósè àti Áárónì Lọ Rí Fáráò
APÁ 3—LÁTI ÌGBÀ ÌDÁǸDÈ KÚRÒ NÍ ÍJÍBÍTÌ SÍ ÀKÓKÒ ỌBA ÀKỌ́KỌ́ NÍ ÍSÍRẸ́LÌ
41 Ejò Bàbà
45 Bí Wọ́n Ṣe La Odò Jọ́dánì Kọjá
46 Odi Jẹ́ríkò
50 Àwọn Obìnrin Méjì Tó Nígboyà
52 Gídíónì àti Ọ̀ọ́dúnrún Ọkùnrin Rẹ̀
55 Ọmọkùnrin Kékéré Kan Sin Ọlọ́run
APÁ 4—LÁTI ÌGBÀ ỌBA ÀKỌ́KỌ́ NÍ ÍSÍRẸ́LÌ SÍ ÌGBÀ ÌGBÈKÙN NÍ BÁBÍLÓNÌ
56 Sọ́ọ̀lù—Ọba Àkọ́kọ́ ní Ísírẹ́lì
59 Ìdí Tí Dáfídì Fi Gbọ́dọ̀ Sá Lọ
67 Jèhóṣáfátì Gbẹ́kẹ̀ Lé Jèhófà
68 Àwọn Ọmọkùnrin Méjì Tó Jí Dìde
69 Ọmọbìnrin Kan Ran Ọkùnrin Alágbára Kan Lọ́wọ́
72 Ọlọ́run Ran Hesekáyà Ọba Lọ́wọ́
73 Ọba Rere Tó Jẹ Kẹ́yìn ní Ísírẹ́lì
75 Ọmọkùnrin Mẹ́rin ní Bábílónì
APÁ 5—LÁTI ÌGBÀ ÌKÓLẸ́RÚLỌ-SÍ-BÁBÍLÓNÌ TÍTÍ DI ÀKÓKÒ TÍTÚN ODI JERÚSÁLẸ́MÙ KỌ́
80 Àwọn Èèyàn Ọlọ́run Kúrò ní Bábílónì
81 Gbígbẹ́kẹ̀lé Ìrànlọ́wọ́ Ọlọ́run
APÁ 6—ÌGBÀ ÌBÍ JÉSÙ SÍ ÀKÓKÒ IKÚ RẸ̀
86 Àwọn Ọkùnrin Tí Ìràwọ̀ Kan Darí
87 Jésù Ọ̀dọ́mọdé Nínú Tẹ́ńpìlì
90 Pẹ̀lú Obìnrin Kan Lẹ́bàá Kànga
91 Jésù Kọ́ Àwọn Èèyàn Lórí Òkè
99 Nínú Yàrá Kan Lórí Òkè Pẹ̀tẹ́ẹ̀sì
100 Jésù Nínú Ọgbà
101 Wọ́n Pa Jésù
APÁ 7—ÌGBÀ TÍ JÉSÙ JÍǸDE SÍ ÌGBÀ TÍ WỌ́N JU PỌ́Ọ̀LÙ SẸ́WỌ̀N
102 Jésù Jíǹde
103 Jésù Wọnú Yàrá Kan Tí Wọ́n Tì Pa
104 Jésù Padà Sọ́run
105 Àwọn Ọmọlẹ́yìn Dúró sí Jerúsálẹ́mù
107 Wọ́n Sọ Sítéfánù Lókùúta Pa
110 Tímótì—Olùrànlọ́wọ́ Tuntun fún Pọ́ọ̀lù
113 Pọ́ọ̀lù ní Róòmù
APÁ 8—OHUN TÍ BÍBÉLÌ SỌ TẸ́LẸ̀ MÁA NÍMÙÚṢẸ
115 Párádísè Tuntun Lórí Ilẹ̀ Ayé
116 Bá A Ṣe Lè Wà Láàyè Títí Láé
wọn Ìbéèrè fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ Ìwé Ìtàn Bíbélì
Ìbéèrè fún ọ̀kọ̀ọ̀kan ìtàn mẹ́rìndínlọ́gọ́fà tá a tò sókè yìí wà ní ojú ewé tó tẹ̀ lé Ìtàn 116.