Ojú Ìwé Tí Wọ́n Kọ Àkọlé Sí/Ojú Ìwé Tí Wọ́n Kọ Orúkọ Òǹṣèwé Sí
Àwọn Ìbéèrè Tí Àwọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè—Àwọn Ìdáhùn Tí Ó Gbéṣẹ́, Apá Kejì
Ìwé Yìí Jẹ́ Ti ․․․․․․․․․․․․․․․․
A Tẹ̀ Ẹ́ ní Ọdún 2008
A tẹ ìwé yìí gẹ́gẹ́ bí ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tí à ń fi ọrẹ àtinúwá ṣètìlẹ́yìn fún
Bá ò bá fi hàn pé ó yàtọ̀, gbogbo ẹsẹ Ìwé Mímọ́ wá láti inú Ìwé Mímọ́ ní Ìtumọ̀ Ayé Tuntun tí a fi àkọtọ́ tó bóde mu kọ
Orúkọ tá a lò fáwọn ọ̀dọ́ tó wà nínú ìwé yìí gan-an kọ́ ni wọ́n ń jẹ́
Ibi Tá A Ti Mú Àwọn Àwòrán:
Ojú ìwé 165: Obìnrin tó ru igi ìdáná: Godo-Foto; Ìlú kan nílẹ̀ Yúróòpù: © 2003 BiblePlaces.com