Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
7 1 Báwo Ni Mo Ṣe Lè Máa Bá Àwọn Òbí Mi Sọ̀rọ̀?
14 2 Kí Nìdí Témi Àtàwọn Òbí Mi Fi Máa Ń Bára Wa Jiyàn?
21 3 Kí Ni Mo Lè Ṣe Tí Màá Fi Ní Òmìnira Sí I?
28 4 Kí Nìdí Tí Dádì àti Mọ́mì Fi Fi Ara Wọn Sílẹ̀?
34 5 Dádì Tàbí Mọ́mì Mi Fẹ́ Ẹlòmíì, Báwo Ni Mo Ṣe Lè Mú Un Mọ́ra?
40 6 Báwo Lọ̀rọ̀ Èmi àti Tẹ̀gbọ́n-Tàbúrò Mi Ṣe Lè Wọ̀ Dáadáa?
49 7 Ṣé Mo Ti Tó Ẹni Tó Lè Lọ Dá Gbé?
57 8 Báwo Ni Mo Ṣe Lè Ní Àwọn Ọ̀rẹ́ Tó Dáa?
64 9 Báwo Ni Mo Ṣe Lè Borí Ìdẹwò?
71 10 Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kí N Máa Tọ́jú Ara Mi?
77 11 Irú Aṣọ Wo Ló Yẹ Kí N Wọ̀?
85 12 Báwo Ni Mo Ṣe Lè Túbọ̀ Dá Ara Mi Lójú?
91 13 Báwo Ni Mo Ṣe Lè Mú Ìbànújẹ́ Kúrò Lọ́kàn Mi?
105 15 Ṣé Ó Burú Kéèyàn Tiẹ̀ Láṣìírí Ni?
111 16 Ṣé Bí Mo Ṣe Ń Kẹ́dùn Dáa Báyìí?
121 17 Kí Nìdí Táyà Mi Fi Máa Ń Já Láti Sọ Ohun Tí Mo Gbà Gbọ́ Nílé Ìwé?
128 18 Ọgbọ́n Wo Ni Mo Lè Dá sí Wàhálà Ilé Ìwé?
134 19 Ǹjẹ́ Mi Ò Ní Pa Ilé Ìwé Tì Báyìí?
142 20 Kí Ni Mo Lè Ṣe Kó Má Bàa Sí Wàhálà Láàárín Èmi àti Olùkọ́ Mi?
150 21 Báwo Ni Mo Ṣe Lè Máa Fọgbọ́n Lo Àkókò Mi?
156 22 Èdè àti Àṣà Tàwọn Òbí Mi Yàtọ̀ sí Tibi Tá À Ń Gbé, Kí Ni Kí N Ṣe?
165 23 Báwo Ni Mo Ṣe Lè Ṣàlàyé Ohun Tí Bíbélì Sọ Nípa Ìbẹ́yà-Kannáà-Lòpọ̀?
172 24 Ṣé Ìbálòpọ̀ Máa Jẹ́ Ká Túbọ̀ Fẹ́ràn Ara Wa?
178 25 Báwo Ni Mo Ṣe Lè Jáwọ́ Nínú Fífọwọ́ Pa Ẹ̀yà Ìbímọ Mi?
183 26 Ṣé Ó Burú Bí Ọkùnrin àti Obìnrin Bá Kàn Gbé Ara Wọn Sùn?
188 27 Kí Nìdí Táwọn Ọkùnrin Kì Í Fi Í Gba Tèmi?
195 28 Kí Nìdí Táwọn Obìnrin Kì Í Fi Í Gba Tèmi?
203 29 Báwo Ni Mo Ṣe Máa Mọ̀ Bóyá Ìfẹ́ Tòótọ́ Ni?
212 30 Ǹjẹ́ A Ti Ṣe Tán Láti Ṣègbéyàwó Báyìí?
221 31 Báwo Ni Màá Ṣe Borí Ẹ̀dùn Ọkàn Mi Bí Àfẹ́sọ́nà Mi Bá Já Mi Sílẹ̀?
228 32 Báwo Ni Mi Ò Ṣe Ní Kó Sọ́wọ́ Àwọn Tó Ń Fipá Báni Lò Pọ̀?
237 33 Àwọn Ewu Wo Ló Yẹ Kí N Mọ̀ Nípa Sìgá Mímu?
246 34 Kí Ló Burú Nínú Mímu Ọtí Ní Àmujù?
252 35 Báwo Ni Mo Ṣe Lè Bọ́ Lọ́wọ́ Lílo Oògùn Olóró?
259 36 Ṣé Mi Ò Ti Sọ Ohun Tó Ń Gbé Ìsọfúnni Jáde Di Bárakú?
265 37 Kí Nìdí Táwọn Òbí Mi Kì Í Fi Í Jẹ́ Kí N Gbádùn Ara Mi?
273 38 Báwo Ni Mo Ṣe Lè Gbádùn Ìjọsìn Ọlọ́run?
282 39 Báwo Ni Ọwọ́ Mi Ṣe Lè Tẹ Àwọn Ohun Tí Mo Fẹ́ Lé Bá?
289 Àfikún: Àwọn Ìbéèrè Tí Àwọn Òbí Ń Béèrè