Ojú Ìwé Tí Wọ́n Kọ Àkọlé Sí/Ojú Ìwé Tí Wọ́n Kọ Orúkọ Òǹṣèwé Sí
Àwọn Ìbéèrè Tí Àwọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè—Àwọn Ìdáhùn Tí Ó Gbéṣẹ́, Apá Kìíní
Ìwé yìí jẹ́ ti ․․․․․
A Tẹ̀ Ẹ́ ní Ọdún 2011
Ìtẹ̀jáde yìí kì í ṣe títà. Ó jẹ́ ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tá à ń fi ọrẹ àtinúwá tì lẹ́yìn
Bá ò bá fi hàn pé ó yàtọ̀, gbogbo ẹsẹ Ìwé Mímọ́ wá láti inú Ìwé Mímọ́ ní Ìtumọ̀ Ayé Tuntun tí a fi àkọtọ́ tó bóde mu kọ
Orúkọ àwọn kan lára àwọn ọ̀dọ́ tá a sọ̀rọ̀ wọn nínú ìwé yìí gan-an kọ́ la lò
Ibi Tá A Ti Mú Àwọn Àwòrán:
Ojú ìwé 241: © Gusto Productions/Photo Researchers, Inc.; ojú ìwé 244: ahọ́n tó ní àrùn jẹjẹrẹ: © Mediscan/Visuals Unlimited, Inc.; òpó ẹ̀jẹ̀ tó ti fẹ́ dí: © Index Stock/Photolibrary; ẹ̀dọ̀fóró tó ní àrùn jẹjẹrẹ: © Arthur Glauberman/Photo Researchers, Inc.; ojú ìwé 245: àwòrán ọpọlọ: © Mediscan/Visuals Unlimited, Inc.; kíndìnrín tó ní àrùn jẹjẹrẹ: © Dr. E. Walker/Photo Researchers, Inc.