Ojú Ìwé Tí Wọ́n Kọ Àkọlé Sí/Ojú Ìwé Tí Wọ́n Kọ Orúkọ Òǹṣèwé Sí
Jésù—Ọ̀nà, Òtítọ́ Àti Ìyè
Ìwé yìí jẹ́ ká mọ̀ nípa ìgbésí ayé Jésù àti iṣẹ́ òjíṣẹ́ rẹ̀. Ó jẹ́ ká mọ irú ẹni tó jẹ́, ohun tó fi kọ́ni àtohun tó ṣe, ó sì tún jẹ́ ká mọ àwọn ẹ̀kọ́ tá a lè rí kọ́ lára Jésù.
Ìtẹ̀jáde yìí kì í ṣe títà. Ó jẹ́ ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tá à ń fi ọrẹ àtinúwá tì lẹ́yìn.
Tó o bá fẹ́ ṣètọrẹ, jọ̀wọ́ lọ sí ìkànnì donate.jw.org.
Tá ò bá fi hàn pé ó yàtọ̀, inú Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun la ti mú gbogbo ẹsẹ Bíbélì tá a lò.
A Tẹ̀ Ẹ́ ní May 2020
Yoruba (jy-YR)
© 2015
WATCH TOWER BIBLE AND TRACT SOCIETY OF PENNSYLVANIA