Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
OJÚ ÌWÉ APÁ ORÍ
APÁ 1—KÍ JÉSÙ TÓ BẸ̀RẸ̀ IṢẸ́ ÒJÍṢẸ́ RẸ̀
10 1 Ìkéde Méjì Látọ̀dọ̀ Ọlọ́run
12 2 Wọ́n Pọ́n Jésù Lé Kí Wọ́n Tó Bí I
14 3 Wọ́n Bí Ẹni Tó Máa Ṣètò Ọ̀nà Sílẹ̀
18 5 Ìgbà Wo Ni Wọ́n Bí Jésù, Ibo sì Ni Wọ́n Bí I Sí?
22 7 Àwọn Awòràwọ̀ Wá Sọ́dọ̀ Jésù
24 8 Wọ́n Sá Lọ Mọ́ Ọba Burúkú Kan Lọ́wọ́
28 10 Jósẹ́fù àti Ìdílé Rẹ̀ Rìnrìn Àjò Lọ sí Jerúsálẹ́mù
30 11 Jòhánù Arinibọmi Ṣètò Ọ̀nà Sílẹ̀
APÁ 2—ÌBẸ̀RẸ̀ IṢẸ́ ÒJÍṢẸ́ JÉSÙ
36 13 Kẹ́kọ̀ọ́ Látinú Bí Jésù Ṣe Kojú Àdánwò
38 14 Jésù Bẹ̀rẹ̀ Sí Í Ní Ọmọ Ẹ̀yìn
40 15 Jésù Ṣe Iṣẹ́ Ìyanu Àkọ́kọ́
42 16 Jésù Ní Ìtara Fún Ìjọsìn Tòótọ́
44 17 Jésù Kọ́ Nikodémù Lẹ́kọ̀ọ́ Ní Òru
46 18 Jòhánù Ń Dín Kù, Àmọ́ Jésù Ń Pọ̀ Sí I
48 19 Jésù Kọ́ Obìnrin Ará Samáríà Kan Lẹ́kọ̀ọ́
APÁ 3—IṢẸ́ ÒJÍṢẸ́ TÓ TA YỌ TÍ JÉSÙ ṢE NÍ GÁLÍLÌ
56 21 Jésù Lọ sí Sínágọ́gù Tó Wà ní Násárẹ́tì
58 22 Àwọn Ọmọ Ẹ̀yìn Mẹ́rin Di Apẹja Èèyàn
60 23 Jésù Ṣe Iṣẹ́ Ìyanu ní Kápánáúmù
62 24 Jésù Mú Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Rẹ̀ Gbòòrò Sí I ní Gálílì
64 25 Jésù Fàánú Hàn sí Adẹ́tẹ̀ Kan, Ó sì Wò Ó Sàn
66 26 “A Dárí Àwọn Ẹ̀ṣẹ̀ Rẹ Jì Ọ́”
70 28 Kí Nìdí Tí Àwọn Ọmọlẹ́yìn Jésù Kò Fi Gbààwẹ̀?
72 29 Ṣé Èèyàn Lè Ṣe Ohun Tó Dáa Lọ́jọ́ Sábáàtì?
74 30 Bí Jésù Ṣe Jẹ́ sí Baba Rẹ̀
76 31 Wọ́n Já Ọkà Jẹ Lọ́jọ́ Sábáàtì
78 32 Kí Ló Bófin Mu ní Sábáàtì?
80 33 Jésù Mú Àsọtẹ́lẹ̀ Àìsáyà Ṣẹ
82 34 Jésù Yan Àwọn Àpọ́sítélì Méjìlá
92 36 Ọ̀gágun Kan Fi Hàn Pé Òun Nígbàgbọ́ Tó Lágbára
94 37 Jésù Jí Ọmọ Opó Kan Dìde
96 38 Jòhánù Fẹ́ Gbọ́rọ̀ Látẹnu Jésù
98 39 Jésù Dẹ́bi fún Ìran Aláìgbọràn
102 41 Agbára Wo Ni Jésù Fi Ń Ṣe Iṣẹ́ Ìyanu?
106 43 Àwọn Àpèjúwe Nípa Ìjọba Ọlọ́run
112 44 Jésù Mú Kí Ìjì Dáwọ́ Dúró Lórí Òkun
114 45 Agbára Jésù Ju Ti Àwọn Ẹ̀mí Èṣù Lọ
116 46 Obìnrin Kan Rí Ìwòsàn Nígbà Tó Fọwọ́ Kan Aṣọ Jésù
118 47 Jésù Jí Ọmọbìnrin Kan Dìde!
120 48 Jésù Ṣe Iṣẹ́ Ìyanu, Àmọ́ Àwọn Ará Násárẹ́tì Kò Gbà Á Gbọ́
122 49 Ó Wàásù, Ó sì Dá Àwọn Àpọ́sítélì Lẹ́kọ̀ọ́ ní Gálílì
124 50 Wọ́n Ṣe Tán Láti Wàásù Láìka Àtakò Sí
126 51 Wọ́n Pa Èèyàn Níbi Ayẹyẹ Ọjọ́ Ìbí Kan
128 52 Ó Fi Ìwọ̀nba Búrẹ́dì àti Ẹja Bọ́ Ẹgbẹẹgbẹ̀rún Èèyàn
130 53 Alákòóso Kan Tó Láṣẹ Lórí Àwọn Nǹkan Àdáyébá
134 55 Ọ̀rọ̀ Jésù Ya Ọ̀pọ̀ Èèyàn Lẹ́nu
136 56 Kí Ló Ń Sọni Di Aláìmọ́?
138 57 Jésù Wo Ọmọbìnrin Kan àti Adití Kan Sàn
140 58 Ó Mú Kí Búrẹ́dì Pọ̀, Ó sì Kìlọ̀ Nípa Ìwúkàrà
146 61 Jésù Wo Ọmọkùnrin Tí Ẹ̀mí Èṣù Ń Yọ Lẹ́nu Sàn
148 62 Ẹ̀kọ́ Pàtàkì Nípa Ẹ̀mí Ìrẹ̀lẹ̀
152 64 Ìdí Tó Fi Yẹ Ká Máa Dárí Jini
154 65 Jésù Ń Kóni Nígbà Tó Ń Lọ sí Jerúsálẹ́mù
APÁ 4—IṢẸ́ ÒJÍṢẸ́ TÍ JÉSÙ PA DÀ ṢE NÍ JÙDÍÀ
158 66 Ó Lọ sí Jerúsálẹ́mù Nígbà Àjọyọ̀ Àwọn Àgọ́ Ìjọsìn
160 67 “Èèyàn Kankan Ò Sọ̀rọ̀ Báyìí Rí”
162 68 Ọmọ Ọlọ́run Ni “Ìmọ́lẹ̀ Ayé”
164 69 Ṣé Ábúráhámù Ni Bàbá Wọn àbí Èṣù?
166 70 Jésù La Ojú Ọkùnrin Kan Tí Wọ́n Bí Ní Afọ́jú
168 71 Àwọn Farisí Gbọ́ Tẹnu Ọkùnrin Afọ́jú Náà
170 72 Jésù Rán Àádọ́rin (70) Ọmọ Ẹ̀yìn Jáde Lọ Wàásù
172 73 Ará Samáríà Kan Fàánú Hàn
174 74 Ẹ̀kọ́ Nípa Aájò Àlejò àti Àdúrà
176 75 Jésù Sọ Ohun Tó Ń Fúnni Láyọ̀
178 76 Farisí Kan Gba Jésù Lálejò
182 78 Jésù Ní Kí Ìríjú Olóòótọ́ Náà Múra Sílẹ̀
184 79 Ìdí Táwọn Èèyàn Náà Fi Máa Pa Run
186 80 Olùṣọ́ Àgùntàn Àtàtà àti Agbo Àgùntàn
188 81 Ọ̀kan Ni Jésù àti Baba, Àmọ́ Jésù Kì Í Ṣe Ọlọ́run
APÁ 5—IṢẸ́ ÒJÍṢẸ́ TÍ JÉSÙ PA DÀ ṢE NÍ ÌLÀ OÒRÙN JỌ́DÁNÌ
192 82 Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Jésù ní Pèríà
194 83 Àwọn Tí Ọlọ́run Pè Síbi Àsè Kan
196 84 Iṣẹ́ Kékeré Kọ́ Lẹ́nì Kan Máa Ṣe Kó Tó Lè Di Ọmọ Ẹ̀yìn
198 85 Àwọn Áńgẹ́lì Máa Ń Yọ̀ Tí Ẹlẹ́ṣẹ̀ Bá Ronú Pìwà Dà
200 86 Ọmọ Tó Sọ Nù Pa Dà Wálé
204 87 Múra Sílẹ̀, Kó O sì Jẹ́ Ọlọ́gbọ́n
206 88 Ọkùnrin Ọlọ́rọ̀ Kan àti Lásárù
210 89 Ó Ń Kọ́ni ní Pèríà Bó Ṣe Ń Lọ sí Jùdíà
216 92 Jésù Wo Adẹ́tẹ̀ Mẹ́wàá Sàn, Ọ̀kan Pa Dà Wá Dúpẹ́
218 93 Ọlọ́run Máa Ṣí Ọmọ Èèyàn Payá
220 94 Ohun Méjì Tó Ṣe Pàtàkì—Àdúrà àti Ẹ̀mí Ìrẹ̀lẹ̀
222 95 Jésù Sọ̀rọ̀ Nípa Ìkọ̀sílẹ̀, Ó sì Fìfẹ́ Hàn Sáwọn Ọmọdé
224 96 Jésù Dáhùn Ìbéèrè Ọ̀dọ́kùnrin Ọlọ́rọ̀ Kan
226 97 Àpèjúwe Àwọn Òṣìṣẹ́ Ọgbà Àjàrà
228 98 Àwọn Àpọ́sítélì Tún Ń Wá Ipò Ọlá
230 99 Jésù La Ojú Àwọn Afọ́jú, Ó sì Ran Sákéù Lọ́wọ́
APÁ 6—IṢẸ́ ÒJÍṢẸ́ TÍ JÉSÙ ṢE KẸ́YÌN
236 101 Wọ́n Lọ Jẹun Nílé Símónì ní Bẹ́tánì
238 102 Ọba Gun Ọmọ Kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ Wọ Jerúsálẹ́mù
240 103 Jésù Fọ Tẹ́ńpìlì Mọ́ Lẹ́ẹ̀kan Sí I
242 104 Lẹ́yìn Táwọn Júù Gbọ́ Ohùn Ọlọ́run, Ṣé Wọ́n Gba Jésù Gbọ́?
244 105 Jésù Fi Igi Ọ̀pọ̀tọ́ Kan Kọ́ Wọn Lẹ́kọ̀ọ́ Nípa Ìgbàgbọ́
246 106 Àpèjúwe Méjì Nípa Ọgbà Àjàrà
248 107 Ọba Kan Pe Àwọn Èèyàn Wá Síbi Ayẹyẹ Ìgbéyàwó
250 108 Ìdáhùn Jésù Ò Jẹ́ Káwọn Ọ̀tá Rẹ̀ Rí I Mú
252 109 Ó Dẹ́bi Fáwọn Aṣáájú Ẹ̀sìn Tó Ń Ta Kò Ó
254 110 Ọjọ́ Tí Jésù Wá sí Tẹ́ńpìlì Kẹ́yìn
256 111 Àwọn Àpọ́sítélì Ní Kí Jésù Fún Àwọn Ní Àmì
260 112 Ẹ̀kọ́ Tí Àpèjúwe Wúńdíá Mẹ́wàá Kọ́ Wa
262 113 Ẹ̀kọ́ Tí Àpèjúwe Tálẹ́ńtì Kọ́ Wa
264 114 Kristi Máa Ṣèdájọ́ Àgùntàn àti Ewúrẹ́
266 115 Ìrékọjá Tí Jésù Máa Ṣe Kẹ́yìn Ń Sún Mọ́lé
268 116 Jésù Kọ́ Wọn Lẹ́mìí Ìrẹ̀lẹ̀ Níbi Ìrékọjá Tó Ṣe Kẹ́yìn
272 118 Wọ́n Jiyàn Nípa Ẹni Tó Tóbi Jù
274 119 Jésù Ni Ọ̀nà, Òtítọ́ Àti Ìyè
276 120 Béèyàn Ṣe Lè Dà Bí Ẹ̀ka Tó ń so Èso, Kó Sì Di Ọ̀rẹ́ Jésù
278 121 “Ẹ Mọ́kàn Le! Mo Ti Ṣẹ́gun Ayé”
280 122 Àdúrà Tí Jésù Gbà Kẹ́yìn Ní Yàrá Tó Wà Lókè
282 123 Jésù Gbàdúrà Nígbà Tí Ẹ̀dùn Ọkàn Bá A
284 124 Júdásì Da Jésù, Wọ́n Sì Fàṣẹ Ọba Mú Jésù
286 125 Wọ́n Mú Jésù Lọ Sọ́dọ̀ Ánásì Àti Káyáfà
288 126 Pétérù Sẹ́ Jésù Nílé Káyáfà
290 127 Jésù Jẹ́jọ́ Níwájú Sàhẹ́ndìrìn Àti Pílátù
292 128 Pílátù Àti Hẹ́rọ́dù Rí I Pé Jésù Ò Jẹ̀bi
294 129 Pílátù Sọ Pé: “Ẹ Wò Ó! Ọkùnrin Náà Nìyí!”
296 130 Ó Fa Jésù Lé Wọn Lọ́wọ́ Kí Wọ́n Lè Lọ Pa Á
298 131 Ọba Kan ń jìyà Láìṣẹ̀ Lórí Òpó Igi
300 132 “Ó Dájú Pé Ọmọ Ọlọ́run Ni Ọkùnrin Yìí”
302 133 Wọ́n Ṣètò Òkú Jésù, Wọ́n Sì Lọ Sin Ín
304 134 Ọlọ́run Ti Jí Jésù Dìde, Ibojì Rẹ̀ Sì Ti Ṣófo!
306 135 Jésù Fara Han Ọ̀pọ̀ Èèyàn Lẹ́yìn Tó Jíǹde
308 136 Ohun Tó Ṣẹlẹ̀ Létíkun Gálílì
310 137 Ọ̀pọ̀ Èèyàn Ló Rí Jésù Ṣáájú Ọjọ́ Pẹ́ńtíkọ́sì