Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
Ẹ̀KỌ́
Ọ̀rọ̀ Ìṣáájú fún Apá 1—Ìṣẹ̀dá
2 Ọlọ́run Dá Ọkùnrin àti Obìnrin Àkọ́kọ́
Ọ̀rọ̀ Ìṣáájú fún Apá 2—Látìgbà Ayé Ádámù sí Ìgbà Àkúnya Omi
3 Ádámù àti Éfà Ṣàìgbọràn sí Ọlọ́run
Ọ̀rọ̀ Ìṣáájú fún Apá 3—Látìgbà Ìkún Omi sí Ìgbà Ayé Jékọ́bù
8 Ábúráhámù àti Sérà Ṣègbọràn sí Ọlọ́run
11 Ọlọ́run Dán Ìgbàgbọ́ Ábúráhámù Wò
13 Jékọ́bù àti Ísọ̀ Parí Ìjà Wọn
Ọ̀rọ̀ Ìṣáájú fún Apá 4—Látìgbà Ayé Jósẹ́fù sí Òkun Pupa
17 Mósè Pinnu Láti Jọ́sìn Jèhófà
18 Iná Ń Jó Lára Igi Kékeré Kan
20 Àwọn Ìyọnu Mẹ́fà Tó Tẹ̀ Lé E
Ọ̀rọ̀ Ìṣáájú fún Apá 5—Nínú Aginjù
28 Kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ Báláámù Sọ̀rọ̀
Ọ̀rọ̀ Ìṣáájú fún Apá 6—Àwọn Onídàájọ́
32 Aṣáájú Tuntun àti Obìnrin Onígboyà Méjì
34 Gídíónì Ṣẹ́gun Àwọn Ará Mídíánì
35 Hánà Gbàdúrà Pé Kí Ọlọ́run Fún Òun ní Ọmọkùnrin
38 Jèhófà Sọ Sámúsìn Di Alágbára
Ọ̀rọ̀ Ìṣáájú fún Apá 7—Dáfídì àti Sọ́ọ̀lù
42 Jónátánì Nígboyà, Ó sì Jẹ́ Adúrótini
Ọ̀rọ̀ Ìṣáájú fún Apá 8—Látìgbà Ayé Sólómọ́nì sí Ìgbà Ayé Èlíjà
44 Wọ́n Kọ́ Tẹ́ńpìlì fún Jèhófà
46 Ìṣẹ̀lẹ̀ Kan Lórí Òkè Kámẹ́lì
49 Ọlọ́run Fìyà Jẹ Ayaba Kan Tó Burú Gan-an
Ọ̀rọ̀ Ìṣáájú fún Apá 9—Látìgbà Ayé Èlíṣà sí Ìgbà Ayé Jòsáyà
51 Jagunjagun àti Ọmọbìnrin Kékeré Kan
55 Áńgẹ́lì Jèhófà Dáàbò Bo Hẹsikáyà
Ọ̀rọ̀ Ìṣáájú fún Apá 10—Látìgbà Ayé Jeremáyà sí Ìgbà Ayé Nehemáyà
57 Jèhófà Rán Jeremáyà Pé Kó Lọ Wàásù
59 Ọ̀dọ́kùnrin Mẹ́rin Ṣègbọràn sí Jèhófà
60 Ìjọba Kan Tó Máa Wà Títí Láé
64 Wọ́n Ju Dáníẹ́lì Sínú Ihò Kìnnìún
65 Ẹ́sítà Gba Àwọn Èèyàn Ẹ̀ Nínú Ewu
66 Ẹ́sírà Kọ́ Àwọn Èèyàn ní Òfin Ọlọ́run
Ọ̀rọ̀ Ìṣáájú fún Apá 11—Jòhánù Arinibọmi àti Jésù
69 Áńgẹ́lì Gébúrẹ́lì Lọ Sọ́dọ̀ Màríà
70 Àwọn Áńgẹ́lì Kéde Pé Wọ́n Ti Bí Jésù
73 Jòhánù Múra Àwọn Èèyàn Sílẹ̀
Ọ̀rọ̀ Ìṣáájú fún Apá 12—Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Jésù
76 Jésù Lé Àwọn Tó Ń Tajà Nínú Tẹ́ńpìlì
77 Obìnrin Kan Wá Pọn Omi Nínú Kànga
78 Jésù Wàásù Nípa Ìjọba Ọlọ́run
80 Jésù Yan Àwọn Àpọ́sítélì Méjìlá
82 Jésù Kọ́ Àwọn Ọmọ Ẹ̀yìn Ẹ̀ Bí Wọ́n Á Ṣe Máa Gbàdúrà
83 Jésù Fún Ọ̀pọ̀ Èèyàn Lóúnjẹ
85 Jésù Wo Ẹnì Kan Sàn Lọ́jọ́ Sábáàtì
Ọ̀rọ̀ Ìṣáájú fún Apá 13—Ọ̀sẹ̀ Tí Jésù Lò Kẹ́yìn Láyé
89 Pétérù Sọ Pé Òun Ò Mọ Jésù Rí
Ọ̀rọ̀ Ìṣáájú fún Apá 14—Ẹ̀sìn Kristẹni Tàn Káàkiri
94 Àwọn Ọmọ Ẹ̀yìn Jésù Gba Ẹ̀mí Mímọ́
98 Ẹ̀sìn Kristẹni Dé Ọ̀pọ̀ Orílẹ̀-Èdè
99 Ẹ̀ṣọ́ Ọgbà Ẹ̀wọ̀n Kan Gbọ́ Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run