Sunday
“Jẹ́ onígboyà, sì jẹ́ kí ọkàn-àyà rẹ jẹ́ alágbára. Bẹ́ẹ̀ ni, ní ìrètí nínú Jèhófà”—SÁÀMÙ 27:14
ÒWÚRỌ̀
- 9:20 Fídíò Orin 
- 9:30 Orin 73 àti Àdúrà 
- 9:40 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Àwọn Ohun Tó Máa Ṣẹlẹ̀ Lọ́jọ́ Iwájú Tó Gba Pé Ká Ní Ìgboyà - Ìkéde “Àlàáfíà àti Ààbò!” (1 Tẹsalóníkà 5:2, 3) 
- Ìparun Bábílónì Ńlá (Ìṣípayá 17:16, 17) 
- Ìkéde Tó Dà Bí Òkúta Yìnyín (Ìṣípayá 16:21) 
- Gọ́ọ̀gù Ti Ilẹ̀ Mágọ́gù Máa Gbéjà Ko Àwọn Èèyàn Ọlọ́run (Ìsíkíẹ́lì 38:10-12, 14-16) 
- Amágẹ́dọ́nì (Ìṣípayá 16:14, 16) 
- Iṣẹ́ Àtúnkọ́ Ńlá (Aísáyà 65:21) 
- Ìdánwò Ìkẹyìn (Ìṣípayá 20:3, 7, 8) 
 
- 11:10 Orin 8 àti Ìfilọ̀ 
- 11:20 ÀSỌYÉ FÚN GBOGBO ÈNÌYÀN: Báwo Ni Ìrètí Àjíǹde Ṣe Ń Jẹ́ Ká Ní Ìgboyà? (Máàkù 5:35-42; Lúùkù 12:4, 5; Jòhánù 5:28, 29; 11:11-14) 
- 11:50 Ìkẹ́kọ̀ọ́ Ilé Ìṣọ́ 
- 12:20 Orin 151 àti Àkókò Ìsinmi 
Ọ̀SÁN
- 1:35 Fídíò Orin 
- 1:45 Orin 5 
- 1:50 FÍÌMÙ: Ìtàn Jónà—Ẹ̀kọ́ Nípa Ìgboyà àti Àánú (Jónà 1-4) 
- 2:40 Orin 71 àti Ìfilọ̀ 
- 2:50 Àwọn Tó Wà Pẹ̀lú Wa Pọ̀ Ju Awọn Tó Wà Lòdì Sí Wa Lọ! (Diutarónómì 7:17, 21; 28:2; 2 Àwọn Ọba 6:16; 2 Kíróníkà 14:9-11; 32:7, 8, 21; Aísáyà 41:10-13) 
- 3:50 Orin Ìparí àti Àdúrà