Saturday
“Ẹ máa jà fitafita torí ìgbàgbọ́”—Júùdù 3
ÀÁRỌ̀
- 9:20 Fídíò Orin 
- 9:30 Orin 57 àti Àdúrà 
- 9:40 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Máa Rántí Pé Àwọn Aláìgbàgbọ́ Lè Di Onígbàgbọ́! - • Àwọn Ará Ìlú Nínéfè (Jónà 3:5) 
- • Àwọn Àbúrò Jésù (1 Kọ́ríńtì 15:7) 
- • Àwọn Gbajúmọ̀ (Fílípì 3:7, 8) 
- • Àwọn Tí Kò Ṣe Ẹ̀sìn Kankan (Róòmù 10:13-15; 1 Kọ́ríńtì 9:22) 
 
- 10:30 Fi Ìwé Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé! Ran Àwọn Èèyàn Lọ́wọ́ Kí Ìgbàgbọ́ Wọn Lè Lágbára (Jòhánù 17:3) 
- 10:50 Orin 67 àti Ìfilọ̀ 
- 11:00 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Ìgbàgbọ́ Ń Mú Kí Wọ́n Ja Àjàṣẹ́gun - • Àwọn Tí Ọkọ Tàbí Aya Wọn Kì Í Ṣe Ẹlẹ́rìí Jèhófà (Fílípì 3:17) 
- • Àwọn Tí Òbí Kan Ṣoṣo Tọ́ (2 Tímótì 1:5) 
- • Àwọn Tí Kò Ní Ọkọ Tàbí Aya (1 Kọ́ríńtì 12:25) 
 
- 11:45 ÌRÌBỌMI: Ẹni Tó Bá Ń Ní Ìgbàgbọ́ Máa Ní Ìyè Àìnípẹ̀kun! (Mátíù 17:20; Jòhánù 3:16; Hébérù 11:6) 
- 12:15 Orin 79 àti Àkókò Ìsinmi 
Ọ̀SÁN
- 1:35 Fídíò Orin 
- 1:45 Orin 24 
- 1:50 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Bí Àwọn Ará Wa Ṣe Ń Fi Hàn Pé Àwọn Nígbàgbọ́ ní . . . - • Áfíríkà 
- • Amẹ́ríkà ti Àríwá 
- • Éṣíà 
- • Oceania 
- • Yúróòpù 
- • Amẹ́ríkà ti Gúúsù 
 
- 2:15 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Jẹ́ Kí Ìgbàgbọ́ Mú Kó O Ṣe Púpọ̀ Sí I - • Kọ́ Èdè Míì (1 Kọ́ríńtì 16:9) 
- • Lọ Síbi Tí Àìní Pọ̀ Sí (Hébérù 11:8-10) 
- • Sapá Kó O Lè Lọ sí Ilé Ẹ̀kọ́ Àwọn Ajíhìnrere (1 Kọ́ríńtì 4:17) 
- • Máa Ṣèrànwọ́ Níbi Iṣẹ́ Ìkọ́lé Ètò Ọlọ́run (Nehemáyà 1:2, 3; 2:5) 
- • Máa “Ya Ohun Kan Sọ́tọ̀” fún Iṣẹ́ Jèhófà (1 Kọ́ríńtì 16:2) 
 
- 3:15 Orin 84 àti Ìfilọ̀ 
- 3:20 FÍDÍÒ: Dáníẹ́lì Nígbàgbọ́ Jálẹ̀ Ìgbésí Ayé Rẹ̀—Apá Kìíní (Dáníẹ́lì 1:1–2:49; 4:1-33) 
- 4:20 “Ẹ Máa Jà Fitafita Torí Ìgbàgbọ́”! (Júùdù 3; Òwe 14:15; Róòmù 16:17) 
- 4:55 Orin 38 àti Àdúrà Ìparí