Sunday
“Tí ẹ bá ní ìgbàgbọ́ . . . ,ó máa ṣẹlẹ̀”—Mátíù 21:21
ÀÁRỌ̀
- 9:20 Fídíò Orin 
- 9:30 Orin 137 àti Àdúrà 
- 9:40 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Àwọn Obìnrin Tí Ìgbàgbọ́ Wọn Lágbára! - • Sérà (Hébérù 11:11, 12) 
- • Ráhábù (Hébérù 11:31) 
- • Hánà (1 Sámúẹ́lì 1:10, 11) 
- • Ọmọbìnrin Ísírẹ́lì Tí Wọ́n Mú Lẹ́rú (2 Ọba 5:1-3) 
- • Màríà Ìyá Jésù (Lúùkù 1:28-33, 38) 
- • Obìnrin Ará Foníṣíà (Mátíù 15:28) 
- • Màtá (Jòhánù 11:21-24) 
- • Àwọn Àpẹẹrẹ Òde Òní (Sáàmù 37:25; 119:97, 98) 
 
- 11:05 Orin 142 àti Ìfilọ̀ 
- 11:15 ÀSỌYÉ FÚN GBOGBO ÈÈYÀN: Ẹ “Ní Ìgbàgbọ́ Nínú Ìhìn Rere” (Máàkù 1:14, 15; Mátíù 9:35; Lúùkù 8:1) 
- 11:45 Orin 22 àti Àkókò Ìsinmi 
Ọ̀SÁN
- 1:35 Fídíò Orin 
- 1:45 Orin 126 
- 1:50 FÍDÍÒ: Dáníẹ́lì Nígbàgbọ́ Jálẹ̀ Ìgbésí Ayé Rẹ̀—Apá Kejì (Dáníẹ́lì 5:1–6:28; 10:1–12:13) 
- 2:40 Orin 150 àti Ìfilọ̀ 
- 2:45 Jẹ́ Kí Ìgbàgbọ́ Sọ Ẹ́ Di Alágbára! (Dáníẹ́lì 10:18, 19; Róòmù 4:18-21) 
- 3:45 Orin Tuntun àti Àdúrà Ìparí