Jẹ́ Kí Ìgbàgbọ́ Ẹ Túbọ̀ Lágbára!
ÒWÚRỌ̀
- 9:40 Ohùn Orin 
- 9:50 Orin 119 àti Àdúrà 
- 10:00 Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Ká Jẹ́ Kígbàgbọ́ Wa Lágbára Báyìí? 
- 10:15 Ṣé Ò Ń Rí “Ẹni Tí A Kò Lè Rí”? 
- 10:30 “Ìgbàgbọ́ Ń Tẹ̀ Lé Ohun Tí A Gbọ́” 
- 10:55 Orin 104 àti Ìfilọ̀ 
- 11:05 “Èso ti Ẹ̀mí Ni . . .Ìgbàgbọ́” 
- 11:35 Ìyàsímímọ́ àti Ìrìbọmi 
- 12:05 Orin 50