Wọnú Ìsinmi Ọlọ́run!
Àárọ̀
- 9:40 Ohùn Orin 
- 9:50 Orin 87 àti Àdúrà 
- 10:00 Báwo La Ṣe Lè Wọnú Ìsinmi Ọlọ́run? 
- 10:15 Ṣé Lóòótọ́ ni “Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run Wà Láàyè”? 
- 10:30 Jẹ́ Kí Jèhófà Máa Tọ́ Ẹ Sọ́nà 
- 10:55 Orin 89 àti Ìfilọ̀ 
- 11:05 Jèhófà Máa Ń Bù Kún Àwọn Tó Bá Ń Ṣègbọràn 
- 11:35 Ìyàsímímọ́ àti Ìrìbọmi 
- 12:05 Orin 32