“Ẹ Máa Hùwà Lọ́nà Tó Yẹ Ìhìn Rere”
Àárọ̀
- 9:40 Ohùn Orin 
- 9:50 Orin 35 àti Àdúrà 
- 10:00 Báwo Ni Ìhìn Rere Ṣe Ń Jẹ́ Kí Ayé Wa Dáa Sí I? 
- 10:15 Àpínsọ Àsọyé: Ohun Tí Ìhìn Rere Mú Kí Wọ́n Ṣe - • Sítéfánù 
- • Fílípì 
- • Ákúílà àti Pírísílà 
- • Títù 
 
- 11:05 Orin 76 àti Ìfilọ̀ 
- 11:15 Máa Tẹ̀ Síwájú Lẹ́nu “Iṣẹ́ Ìfọkànsin Ọlọ́run” 
- 11:35 Ìrìbọmi: Máa “Ṣègbọràn sí Ìhìn Rere” 
- 12:05 Orin 37 
Ọ̀sán
- 1:20 Ohùn Orin 
- 1:30 Orin 56 àti Àdúrà 
- 1:35 Àsọyé fún Gbogbo Èèyàn: Kí Ló Mú Kó O Gbà Pé Òótọ́ Lohun Tó O Gbà Gbọ́? 
- 2:05 Ìkẹ́kọ̀ọ́ Ilé Ìṣọ́ 
- 2:35 Orin 24 àti Ìfilọ̀ 
- 2:45 Àpínsọ Àsọyé: “À Ń Dámọ̀ràn Ara Wa Bí Òjíṣẹ́ Ọlọ́run . . . ” - • Tá A Bá Ní Ìfaradà 
- • Tá A Bá Jẹ́ Onínúure 
- • Tá A Bá Jẹ́ Olóòótọ́ 
 
- 3:30 Báwo Ni Ìhìn Rere Ṣe Ń Kọ́ Wa? 
- 4:00 Orin 29 àti Àdúrà