“Máa Jọ́sìn Ní Ẹ̀mí àti Òtítọ́”
Àárọ̀
- 9:40 Ohùn Orin 
- 9:50 Orin 85 àti Àdúrà 
- 10:00 “Irú Àwọn Ẹni Yìí Ni Baba Ń Wá” 
- 10:15 Àpínsọ Àsọyé: “Máa Jọ́sìn Ní Ẹ̀mí” - • Tó O Bá Fẹ́ Lóye Ìtọ́sọ́nà Jèhófà 
- • Tó O Bá Rẹ̀wẹ̀sì 
- • Tó O Bá Fẹ́ Ṣe Púpọ̀ Sí I 
 
- 11:05 Orin 88 àti Ìfilọ̀ 
- 11:15 Bá A Ṣe Ń “Fi Òtítọ́ Hàn Kedere” 
- 11:35 Ìrìbọmi: Àǹfààní Wo Lo Máa Rí Tó O Bá Ṣèrìbọmi? 
- 12:05 Orin 51 
Ọ̀sán
- 1:20 Ohùn Orin 
- 1:30 Orin 72 àti Àdúrà 
- 1:35 Àsọyé fún Gbogbo Èèyàn: Báwo La Ṣe Lè Mọ Ìyàtọ̀ Láàárín Ohun Tó Tọ́ Àtohun Tí Kò Tọ́? 
- 2:05 Ìkẹ́kọ̀ọ́ Ilé Ìṣọ́ 
- 2:35 Orin 56 àti Ìfilọ̀ 
- 2:45 Àpínsọ Àsọyé: “Máa Jọ́sìn Ní . . . Òtítọ́” - • Nínú Ìdílé 
- • Nínú Ayé Táwọn Èèyàn Ò Ti Wà Níṣọ̀kan 
- • Nígbà Tí Nǹkan Bá Le 
 
- 3:30 “Ra Òtítọ́, Má sì Tà Á” 
- 4:00 Orin 29 àti Àdúrà