Ìwé-Ìròhìn Onísìn Wo ni Ìpínkiri Rẹ̀ Gbòòrò Julọ?
Ilé-ìṣọ́nà! Nisinsinyi iye tí ó lé ní 15 million ẹ̀dà ìtẹ̀jáde kọọkan ìwé-ìròhìn yii ni a ńtẹ̀ ní iye èdè tí wọn ju ọgọ́rùn-ún lọ. Iwọ lè rí Ilé-ìṣọ́nà gbà ní eyikeyii ninu awọn èdè tí a tòlẹ́sẹẹsẹ sí ojú-ìwé 2. San àsansílẹ̀-owó ọlọ́dún kan fun un, kí o sì maa gba ìtẹ̀jáde meji lóṣooṣù, kìkì nipa kíkọ ọ̀rọ̀ kún àlàfo ìsàlẹ̀ yii kí o sì gé e ranṣẹ sí wa.
Emi yoo fẹ́ lati gbà ìsọfúnni lórí bí mo ṣe lè maa gbà Ilé-ìṣọ́nà déédéé. (Kọ̀wé sí adirẹsi tí ó wà nísàlẹ̀ yii fun ìsọfúnni.)