Atọ́ka Kókó Ẹ̀kọ́ Fún Ilé Ìṣọ́ 1997
Tí ń tọ́ka ọjọ́ ìtẹ̀jáde tí ọ̀rọ̀ ẹ̀kọ́ fara hàn
ÀWỌN ẸLẸ́RÌÍ JÈHÓFÀ
Àpéjọpọ̀ Àgbáyé, 4/1
Àpéjọpọ̀ “Àwọn Ońṣẹ́ Àlàáfíà Ọlọ́run”, 1/15
Àwọn Ẹni Bí Àgùntàn ní Ilẹ̀ Navajo, 8/15
Bíbomi Paná Ẹ̀sùn Èké ní Ilẹ̀ Faransé, 3/15
Èé Ṣe Tí Ó Fi Yẹ Kí Gbogbo Wa Yin Ọlọ́run? (ìrírí), 1/1
Fífi Ìfẹ́ Hàn sí Àwọn Tí Ó Nílò Ìrànwọ́, 10/1
Ìhìn Rere Párádísè ní Tahiti, 10/15
Ìjagunmólú ní Ilẹ̀ Gíríìsì, 2/1
Ìkẹ́kọ̀ọ́yege Gilead, 6/1, 12/1
Ìlànà Ìwà Híhù Nínú Ìṣègùn, àti Iṣẹ́ Abẹ Láìlo Ẹ̀jẹ̀, 2/15
Ilé Ẹjọ́ Gíga Jù Lọ Ti Connecticut Gbé Ẹ̀tọ́ Aláìsàn Lárugẹ, 8/1
Inúnibíni Ìjọba Nazi, 8/15
Ìwé Pẹlẹbẹ Béèrè, 1/15
Mímú Òmìnira Tẹ̀mí Wá fún Àwọn Ẹlẹ́wọ̀n (Mexico), 2/15
“Ọ̀kan Péré Lára Ọ̀pọ̀ Ìgbésí Ayé Tí O Nípa Lé Lórí,” 3/1
Ọrẹ, 11/1
Ṣíṣèbẹ̀wò sí Pápá Míṣọ́nnárì Ilẹ̀ Wa (C. Seymour), 6/15
Wọ́n “Ra Òtítọ́”! (Gánà), 12/15
ÀWỌN OLÙPÒKÌKÍ ÌJỌBA RÒYÌN
2/1, 3/1, 4/1, 6/1, 7/1, 8/1, 9/1, 10/1, 12/1
BÍBÉLÌ
Báwo Ni Ọlọ́run Ṣe Mí Sí I? 6/15
Bí Bíbélì Ṣe Tẹ̀ Wá Lọ́wọ́, 8/15, 9/15, 10/15
Bíbélì Makarios, 12/15
Ìwé Tí Kò Láfiwé, 6/15
ÌBÉÈRÈ LÁTI ỌWỌ́ ÀWỌN ÒǸKÀWÉ
Àwọn Ẹlẹ́rìí ha ń ṣe iṣẹ́ ìyàsọ́tọ̀ nísinsìnyí bí? 7/1
Àwọn tí ó yí pa dà yóò ha wà nígbà “ìpọ́njú ńlá”? 2/15
Ìfìyà-ikú-jẹni, 6/15
Ìlò ibi ọmọ àti ìwọ́, 2/1
Ìmúṣekedere lórí “ìran” (Mt 24:34) ha kan 1914? 6/1
“Ìran” (Mt 24:34) ha mú kí òpin jìnnà bí? 5/1
Iṣẹ́ ajé—èé ṣe tí a fi nílò ìwé àdéhùn? 8/1
Ojúṣe ìgbìmọ̀ ìgbẹ́jọ́, 4/1
Tetragrammaton ha fara hàn nínú ìwé Mátíù ti Shem-Tob? 8/15
Yíyan ọmọdé láàyò fún ìbálòpọ̀, 2/1
ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI ÀNÍMỌ́ KRISTẸNI
Àìlábòsí—Èèṣì Tàbí Yíyàn? 5/15
Àìlera Ẹ̀dá Ènìyàn Ń Fi Hàn Pé Agbára Jèhófà Pọ̀, 6/1
Ayẹyẹ Ìgbéyàwó Tí Ń Bọlá fún Jèhófà, 4/15
Bíbọlá fún Àwọn Òbí Àgbàlagbà, 9/1
Èé Ṣe Tí Ó Fi Yẹ Kí O Fẹjọ́ Ẹni Tí Ó Hùwà Ibi Sùn? 8/15
Ẹ̀mí Ayé Ha Ń Bà Ọ́ Jẹ́ Bí? 10/1
Ẹ̀rí Ọkàn, 8/1
‘Fi Àwọn Ohun Ìní Tí Ó Níye Lórí Bọlá fún Jèhófà’—Lọ́nà Wo? 11/1
Fífòyemọ Ìlànà, 10/15
Gba Ẹ̀mí Ọmọ Rẹ Là! 7/15
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Ìdílé, 8/1
Ìrètí Nínú Àìsírètí, 5/15
Ìwà Títọ́, 5/1
Ìwọ Ha Jẹ́ Ọ̀rẹ́ Ọlọ́run Bí?—Àdúrà Fi Hàn, 7/1
Ìwọ Ha Ń Bẹ̀rù Láti Gbẹ́kẹ̀ Lé Àwọn Ẹlòmíràn Bí? 3/1
Ìwọ Ha Ń Jẹun Kánú Nípa Tẹ̀mí Bí? 4/15
Ìwọ Ha Ń Yán Hànhàn Láti Ṣiṣẹ́ Sìn ní Kíkún Sí I Bí? 3/15
Kórìíra Ohun Búburú Tẹ̀gàntẹ̀gàn, 1/1
Máa Bá A Lọ Ní Jíjẹ́ Aláyọ̀ Nínú Iṣẹ́ Ìsìn Alákòókò Kíkún, 9/15
Ǹjẹ́ Gbogbo Àròyé Ni Ó Burú? 12/1
Ṣọ́ra fún ‘Àwọn Epikúréì,’ 11/1
Ṣọ́ra fún Níní Èrò Òdì Síni, 5/15
ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ
“Dípò Wúrà, Mo Rí Dáyámọ́ńdì” (M. Kaminaris), 3/1
Èrè fún Iṣẹ́ Ìsìn Ọlọ́wọ̀ (H. Bloor), 12/1
Fífi Sùúrù Dúró De Jèhófà Láti Ìgbà Èwe Mi (R. Graichen), 8/1
Ìgbésí Ayé Tí N Kò Kábàámọ̀ Rí (P. Obrist), 7/1
Ìgbọ́kànlé Nínú Jèhófà Mú Mi Dúró (A. Paixão), 2/1
Jèhófà Ń Hùwà Lọ́nà Ìdúróṣinṣin (P. Palliser), 6/1
Mo Dúpẹ́ fún Àkókò Gígùn Tí Mo Lò Nínú Iṣẹ́ Ìsìn Jèhófà (O. Mydland), 10/1
Mo Dúpẹ́ Mo Tọ́pẹ́ Dá (J. Wynn), 9/1
Mo Kẹ́kọ̀ọ́ Òtítọ́ Bíbélì ní Romania (G. Romocean), 4/1
Mo Rí “Ẹni Kékeré” Tí Ó Di “Alágbára Orílẹ̀-Èdè” (W. Dingman), 11/1
Ọlọ́run Ni Ibi Ìsádi àti Okun Mi (C. Müller), 5/1
Yíyááfì Ohun Púpọ̀ Nítorí Ohun Tí Ó Tóbi Jù Ú Lọ (J. Owó Bello), 1/1
JÈHÓFÀ
Ó Ń Fi Ìyọ́nú Ṣàkóso, 12/15
“Ọlọ́run Àlàáfíà” Bìkítà fún Àwọn Tí A Ń Pọ́n Lójú, 4/15
Ọlọ́run Tí Ó Jẹ́ Ẹni Gidi, 10/1
JÉSÙ KRISTI
A Kókìkí Jésù Gẹ́gẹ́ Bíi Mèsáyà àti Ọba, 3/1
LÁJORÍ ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́
“Akọ àti Abo Ni Ó Dá Wọn,” 6/15
Àlàáfíà Kò Sí fún Àwọn Èké Ońṣẹ́! 5/1
Àlàáfíà Tòótọ́—Láti Orísun Wo? 4/15
Aláyọ̀ Ni Àwọn Tí Wọ́n Wà Lójúfò! 3/1
A Polongo Àwọn Ońṣẹ́ Àlàáfíà Ọlọ́run Ní Aláyọ̀, 5/1
Àṣírí Tí Àwọn Kristẹni Kò Jẹ́ Pa Mọ́! 6/1
Àwọn Ìbùkún Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Aṣáájú Ọ̀nà, 10/15
Àwọn Kristẹni àti Ayé Aráyé, 11/1
A Yà Wọ́n Sọ́tọ̀ Láti Jẹ́ Onídùnnú Olùyìn Jákèjádò Ayé, 7/1
“Báyìí Ni Ọlọ́run Ṣe Nífẹ̀ẹ́ Wa,” 2/1
“Bí Ó Tilẹ̀ Jẹ́ Pé Ẹ Kò Rí I Rí, Ẹ Nífẹ̀ẹ́ Rẹ̀,” 2/1
Dídá Àwọn Ońṣẹ́ Tòótọ́ Mọ̀ Yàtọ̀, 5/1
Ẹ Jẹ́ Kí A Di Ìgbàgbọ́ Wa Ṣíṣeyebíye Mú Ṣinṣin! 9/1
Ẹ Jẹ́ Kí Gbogbo Wa Yin Jèhófà Lógo! 1/1
Ẹ Jẹ́ Kí Ìfẹ́ Ará Tí Ẹ̀yin Ní Máa Bá A Lọ! 8/1
‘Ẹ Máa Bá A Lọ Ní Dídáríji Ara Yín Lẹ́nì Kíní Kejì,’ 12/1
Ẹ Máa Fi Ọjọ́ Jèhófà Sọ́kàn Pẹ́kípẹ́kí, 9/1
Ẹ Mọ́kàn Le Bí Ìdáǹdè Ṣe Ń Sún Mọ́lé, 4/1
Fífi Ìdúróṣinṣin Gbé Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run Tí A Mí Sí Lárugẹ, 10/1
Fífi Ìdúróṣinṣin Sìn Pẹ̀lú Ètò Àjọ Jèhófà, 8/1
“Gbogbo Ojúṣe Ènìyàn,” 2/15
Ìdáǹdè Sínú Ayé Tuntun Òdodo, 4/1
Ìgbàgbọ́ Ń Jẹ́ Kí A Mú Sùúrù, Kí A Sì Kún fún Àdúrà, 11/15
Ìgbàgbọ́ Ń Sún Wa Ṣiṣẹ́! 11/15
Ìgbésí Ayé Rẹ—Kí Ni Ète Rẹ̀? 2/15
Ìṣàbójútó Lọ́nà Ìṣètò Ìṣàkóso Ọlọ́run ní Sànmánì Kristẹni, 5/15
Ìwọ Ha Ń Gbé Ìgbésí Ayé fún Òní Tàbí fún Ọjọ́ Ọ̀la Ayérayé? 8/15
Ìwọ Ha Ń Lépa Ìwà Funfun Bí? 7/15
Ìwọ Ha Wà Ní Sẹpẹ́ De Ọjọ́ Jèhófà Bí? 3/1
Ìwọ Yóò Ha Jẹ́ Olùṣòtítọ́ Bí Èlíjà Bí? 9/15
“Ìyèkooro Èrò Inú” Bí Òpin Ti Ń Sún Mọ́lé, 8/15
Jèhófà Mọyì Iṣẹ́ Ìsìn Rẹ Tí O Ṣe Tọkàntọkàn, 10/15
Jèhófà—Ọlọ́run Tí Ń Ṣí Àṣírí Payá, 6/1
Jèhófà, Ọlọ́run Tí “Ó Múra Àtidáríjì,” 12/1
Jẹ́ Kí Ìfòyemọ̀ Dáàbò Bò Ọ́, 3/15
Jẹ́ Kí Ọkàn Àyà Rẹ Fà sí Ìfòyemọ̀, 3/15
Kí Ni Ọlọ́run Ń Béèrè Lọ́wọ́ Wa? 1/15
Láìfi Àdánwò Pè, Rọ̀ Mọ́ Ìgbàgbọ́ Rẹ! 11/15
Líla “Ọjọ́ Jèhófà” Já, 12/15
Máa Lépa Àlàáfíà Ọlọ́run Nínú Ìgbésí Ayé Ìdílé, 6/15
Máa Wá Àlàáfíà Tòótọ́, Kí O sì Máa Lépa Rẹ̀! 4/15
Nígbà Tí Jésù Bá Wá Nínú Ògo Ìjọba, 5/15
Ògo Tí Ó Pọ̀ Ju Ti Ìṣáájú Lọ Tí Ilé Jèhófà Ní, 1/1
“Olúwa Kì Yóò Ṣá Àwọn Ènìyàn Rẹ̀ Tì,” 7/1
Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run Dúró Láéláé, 10/1
Pípa Ìwà Funfun Mọ́ Nínú Ayé Tí Ó Kún fún Ìwà Abèṣe, 7/15
Ríran Àwọn Ẹlòmíràn Lọ́wọ́ Láti Mọ Àwọn Ohun Tí Ọlọ́run Ń Béèrè, 1/15
Ṣe Ìpolongo Ní Gbangba fún Ìgbàlà, 12/15
Ṣíṣiṣẹ́sìn Gẹ́gẹ́ Bí Àwọn Ońṣẹ́ Àlàáfíà Ọlọ́run, 1/15
Ṣọ́ra fún Àwọn Olùkọ́ Èké! 9/1
Ta Ni Yóò La “Ọjọ́ Jèhófà” Já? 9/15
Wọ́n Wà Nínú Ayé Ṣùgbọ́n Wọn Kì Í Ṣe Apá Kan Rẹ̀, 11/1
Ọ̀KAN-Ò-JỌ̀KAN
Àrísítákọ́sì, 9/15
Àtúnwáyé, 5/15
Àwọn Afarapitú Lórí Òkè Ńlá Ti Àpáta Gàǹgà, 7/15
Àwọn Àjọ̀dún Ìkórè Ha Dùn Mọ́ Ọlọ́run Nínú Bí? 9/15
Àwọn Ẹgbẹ́ Ìmùlẹ̀, 6/1
Àwọn Ọ̀dọ́—Wọ́n Ha Ní Ọjọ́ Ọ̀la Tí Ó Fọkàn Ẹni Balẹ̀ Bí? 12/1
Àwọn Ọjọ́ Ìkẹyìn, 4/1
Àwọn Tí A Ń Pọ́n Lójú Yóò Ha Ní Àlàáfíà Láé Bí? 4/15
Àyè Orin Nínú Ìjọsìn Òde Òní, 2/1
Ayọ̀—Kí Ni Àṣírí Rẹ̀? 10/15
Éhúdù, 3/15
Énọ́kù, 1/15
Epafírásì, 5/15
Ẹgbẹ́ Arinkinkin-Mọ́lànà, 3/1
Ẹ̀ṣẹ̀, 7/15
“Ẹ̀wù Mímọ́ Trier,” 4/1
Ibo Ni A Ti Lè Rí Ayọ̀ Tòótọ́? 3/15
“Ìdájọ́ Tí A Gbé Ka Ìwádìí”—Ẹ̀kọ́ Tí A Gbé Ka Bíbélì Ha Ni Bí? 7/15
Ìgbà Tí Ìyà Kò Ní Sí Mọ́, 2/15
Ìgbàgbọ́ Ha Nílò Iṣẹ́ Ìyanu Bí? 3/15
Ìgbàlà, 8/15
Ìgbéyàwó Ọdún 403 Wà Nínú Ìjọ̀ngbọ̀n (Ṣọ́ọ̀ṣì Sweden), 4/1
Ìgbéyàwó Tí Kò Ní Ète Ìbálòpọ̀ Nínú Ha Ni Bí? (Màríà), 10/15
Ìgbẹ́kẹ̀lé Nínú Ayé Aláìpé, 5/1
Ilé Ẹ̀kọ́ Onílé Gbígbé, 3/15
Iṣẹ́ Ìyanu Nìkan Kò Gbé Ìgbàgbọ́ Ró, 3/15
Ìṣọ̀kan Ayé, 11/1
Ìwòsàn, 7/1
Jerúsálẹ́mù Ní Àkókò Tí A Kọ Bíbélì, 6/15
Kérésìmesì, 12/15
Mishnah, 11/15
Naḥmanides Ha Fi Hàn Pé Èké Ni Ẹ̀sìn Kristẹni Bí? 4/15
O Ha Ń Yán Hànhàn fún Ayé Onídàájọ́ Òdodo? 11/15
Òfin Mẹ́wàá, 12/1
Òmìnira Ìsìn, 2/1
Ónẹ́sífórù, 11/15
Ṣékémù—Ìlú Tí Ń Bẹ Nínú Àfonífojì, 2/1
Ṣúnémù—A Mọ̀ Ọ́n fún Ìfẹ́ àti Ìwà Ipá Rẹ̀, 10/1
“Tẹ́ńpìlì Ọlọ́run” àti Àwọn Òrìṣà ní Ilẹ̀ Gíríìsì, 2/15
Tẹ́tíọ́sì, 7/15
Wọ́n Tòṣì Síbẹ̀ Wọ́n Lọ́rọ̀, 9/15
WỌ́N ṢE ÌFẸ́ JÈHÓFÀ
A Kókìkí Jésù Gẹ́gẹ́ Bíi Mèsáyà àti Ọba, 3/1
A San Èrè fún Ìgbàgbọ́ Àwọn Òbí (àwọn òbí Mósè), 5/1
Àpẹẹrẹ Ìfara-ẹni-rúbọ, Ìdúróṣinṣin (Èlíṣà), 11/1
Bàbá Tí Ó Ṣe Tán Láti Dárí Jini (àkàwé ọmọkùnrin onínàákúnàá), 9/1
Obìnrin Ọlọgbọ́n Kòòré Ìjábá (Ábígẹ́lì), 7/1
Wíwá Aya fún Aísíìkì, 1/1