Atọ́ka Àwọn Àkòrí Inú Ilé Ìṣọ́ Ọdún 2006
Ó ń tọ́ka sí Ilé Ìṣọ́ tí àpilẹ̀kọ kọ̀ọ̀kan ti jáde
ÀWỌN ẸLẸ́RÌÍ JÈHÓFÀ
Àmì Onígun Mẹ́ta Aláwọ̀ Àlùkò, 2/15
Arúgbó Kan Tí Kò Dá Wà (F. Rivarol), 8/15
Àwọn Èèyàn Ọlọ́run Ń Jùmọ̀ Kọ́lé, 11/1
Àwọn Ìlú Àdádó ní Bolivia, 2/15
Àwọn Tó Ṣẹ̀ṣẹ̀ Di Ara Ìgbìmọ̀ Olùdarí, 3/15
Daniel àti Káàdì Ìpàdé Àgbègbè Rẹ̀, 11/1
Guinea, 10/15
Haiti, 12/15
Ìbẹ̀wò Kan Tó Yí Èrò Mi Padà, 7/1
Ìgbàgbọ́ Rẹ̀ Fún Àwọn Ẹlòmíràn Níṣìírí (Erékùṣù Canary), 7/1
Ìkẹ́kọ̀ọ́yege Nílé Ẹ̀kọ́ Gílíádì, 1/1, 7/1
Ilé Ẹ̀kọ́ Iṣẹ́ Òjíṣẹ́, 11/15
Ìròyìn Láti Ilẹ̀ Áfíríkà 3/1
Ìtẹ̀síwájú Tó Dùn Mọ́ni (Taiwan), 8/15
Kọ́ Àwọn Ọmọ Rẹ Kí Wọ́n Lè Máa Dáhùn Nípàdé, 11/15
“Látòní Yìí Lọ, Mo Gbà Pé Ọlọ́run Wà” (Czech), 7/15
“Máa Bá Ọ̀rọ̀ Rẹ Lọ!” (ọmọ iléèwé kan ní Rọ́ṣíà), 3/1
‘Mi Ò Mọ̀ Pé Mo Lè Parí Ẹ̀kọ́ Mi Lọ́nà Tó Dára Tó Báyìí’ (Sípéènì), 7/1
“Nítorí Ọmọ Ọdún Mẹ́sàn-Án Kan,” 9/1
Ǹjẹ́ A Lè Tọ́ Adájọ́ Sọ́nà? 12/1
Panama, 4/15
Uganda, 6/15
Wọ́n Kọ́kọ́ Lé Wọn Dànù, Lẹ́yìn Náà Wọ́n Wá Di Ọ̀rẹ́ (Peru), 1/1
BÍBÉLÌ
Àwọn Ìwé Inú Bíbélì (Ìwé Muratori), 2/15
Àwọn Kókó Pàtàkì Látinú Ìwé Ẹ́sírà, 1/15
Àwọn Kókó Pàtàkì Látinú Ìwé Nehemáyà, 2/1
Àwọn Kókó Pàtàkì Látinú Ìwé Ẹ́sítérì, 3/1
Àwọn Kókó Pàtàkì Látinú Ìwé Jóòbù, 3/15
Àwọn Kókó Pàtàkì Látinú Sáàmù, Ìwé Kìíní, 5/15
Àwọn Kókó Pàtàkì Látinú Sáàmù, Ìwé Kejì, 6/1
Àwọn Kókó Pàtàkì Látinú Sáàmù, Ìwé Kẹta àti Ìkẹrin, 7/15
Àwọn Kókó Pàtàkì Látinú Sáàmù, Ìwé Karùn-ún, 9/1
Àwọn Kókó Pàtàkì Látinú Ìwé Òwe, 9/15
Àwọn Kókó Pàtàkì Látinú Ìwé Oníwàásù, 11/1
Àwọn Kókó Pàtàkì Látinú Ìwé Orin Sólómọ́nì, 11/15
Àwọn Kókó Pàtàkì Látinú Ìwé Aísáyà, Apá Kìíní, 12/1
“Ẹ Jẹ́ Ká Fi Ẹsẹ Ìwé Mímọ́ Wé Ará Wọn,” 8/15
‘Ibi Tí Wọ́n Kọ Ọ̀rọ̀ Bíbélì sí, Tí Ọjọ́ Rẹ̀ Pẹ́ Jù Lọ,’ 1/15
Lílóye Bíbélì, 4/1
“Mo Mà Nífẹ̀ẹ́ Òfin Rẹ O!” 9/15
Ǹjẹ́ Bíbélì Káni Lọ́wọ́ Kò Jù? 10/1
Ọkùnrin Tó Ṣiṣẹ́ Takuntakun (Seraphim), 5/15
Títẹ Bíbélì—Christophe Plantin, 11/15
ÌBÉÈRÈ LÁTI ỌWỌ́ ÀWỌN ÒǸKÀWÉ
Bí ẹni tí ẹ̀mí èṣù ń dà láàmú ṣe lè bọ́, 4/15
Ewu mẹ́ta wo ni Jésù kìlọ̀ nípa rẹ̀? (Mt 5:22), 2/15
Ìgbà tí jàǹbá ọkọ̀ bá yọrí sí ikú, 9/15
“Ìwọ kò gbọ́dọ̀ se ọmọ ẹran nínú wàrà ìyá rẹ̀” (Ẹk 23:19), 4/1
Kí ló ń mú kí “àwọn ohun fífani-lọ́kàn-mọ́ra” wá sílé ìjọsìn tòótọ́? (Hag 2:7), 5/15
“Kò sí ènìyàn kankan tí ó ti gòkè re ọ̀run bí kò ṣe ẹni tí ó sọ kalẹ̀” (Jo 3:13), 6/15
Nínú Òfin Mósè, kí nìdí táwọn ohun kan tó ní í ṣe pẹ̀lú ìbálòpọ̀ fi lè sọ èèyàn di aláìmọ́? 6/1
Ǹjẹ́ a lè yọ ẹnì kan lẹ́gbẹ́ nítorí ìwà àìmọ́? 7/15
Ǹjẹ́ èèyàn lè dẹ́ṣẹ̀ kó sì kú lẹ́yìn ìdánwò ìkẹyìn? 8/15
Ǹjẹ́ Jósẹ́fù woṣẹ́? (Jẹ 44:5), 2/1
Ohun tó wà nínú àpótí májẹ̀mú, 1/15
Ṣé ‘a kò gba Mósè láyè mọ́ láti jáde’ ni? (Di 31:2), 10/1
Ṣé àwọn obìnrin ní láti “dákẹ́” nínú ìjọ? (1Kọ 14:34), 3/1
Ṣé Jésù ni “ọgbọ́n” kó tó di èèyàn? (Owe orí 8), 8/1
Ṣé Jésù kò bọ̀wọ̀ fún ìyá rẹ̀ ni? (Jo 2:4), 12/1
Ṣé Ọlọ́run máa pa ilẹ̀ ayé run? (Sm 102:26), 1/1
ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI ÀNÍMỌ́ KRISTẸNI
‘Afọgbọ́nhùwà Ni Ẹni Tó Ń Ka Ìbáwí Sí’ (Owe orí 15), 7/1
Àkókò Kò Ṣeé Tọ́jú Pa Mọ́, Lò Ó Dáadáa, 8/1
Àwọn Arúgbó Lè Rí Ìtùnú, 6/1
Bí “Ohun Èlò Tí Ó Túbọ̀ Jẹ́ Aláìlera” Ti Ṣeyebíye Tó, 5/15
Bí Ọ̀rọ̀ Ṣe Lè Wọ Ọmọ Kékeré Lọ́kàn, 5/1
Bó O Ṣe Lè Ṣe Ìpinnu Tó Bá Ìfẹ́ Ọlọ́run Mu, 4/15
Ẹ̀kọ́ Nípa Ẹ̀mí Ìgbéraga àti Ẹ̀mí Ìrẹ̀lẹ̀, 6/15
Ẹ̀yin Òbí—Ẹ Jẹ́ Àpẹẹrẹ Rere Fáwọn Ọmọ Yín, 4/1
Ìbẹ̀rù Ọlọ́run Jẹ́ “Ìbáwí Síhà Ọgbọ́n” (Owe orí 15), 8/1
Ìjùmọ̀sọ̀rọ̀ Láàárín Tọkọtaya, 4/15
Ìṣòtítọ́ Lérè, 12/1
Jẹ́ Kí Ṣíṣe Àṣàrò Máa fún Ọ Láyọ̀, 1/1
Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Ká Máa Ṣe Ohun Tó Tọ́? 11/15
Máa Ṣàánú Àwọn Tálákà, 5/1
Má Bẹ̀rù—Jèhófà Wà Pẹ̀lú Rẹ, 5/1
Nígbà Tí Èèyàn Wa Kan Bá Fi Jèhófà Sílẹ̀, 9/1
Ojúlówó Aásìkí, 2/1
“Òmìnira Ọ̀rọ̀ Sísọ,” 5/15
Ọjọ́ Ìgbéyàwó, 10/15
Ọmọ Títọ́, 11/1
Ọ̀ràn Tó Kàn Ọ́ Gbọ̀ngbọ̀n, 11/15
‘Ọ̀rọ̀ Tó Bọ́ Sákòókò Mà Dára O,’ 1/1
Sísìn ní Ìjọ Tí Wọ́n Ti Ń Sọ Èdè Ilẹ̀ Òkèèrè, 3/15
Tó O Bá Wà Nípò Àṣẹ, Máa Fara Wé Kristi, 4/1
Wàá Ní Ìbàlẹ̀ Ọkàn Tó O Bá Ń Fi Ìlànà Bíbélì Sílò, 6/1
ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ
A Jà Fitafita Ká Lè Dúró Gbọn-in Nínú Ìgbàgbọ́ (R. Brüggemeier), 12/1
A Mọ Ohun Tó Tọ́, A sì Ṣe É (H. Sanderson), 3/1
A Pinnu Láti Sin Jèhófà (R. Kuokkanen), 4/1
Bí Mo Ṣe Jàǹfààní Látinú Jíjẹ́ Tí Ìdílé Mi Jẹ́ Adúróṣinṣin (K. Cooke), 9/1
Inú Rẹ̀ Máa Ń Dùn sí Òfin Jèhófà (A. Schroeder), 9/15
Jèhófà Jẹ́ Kí N Rí Òun (F. Clark), 2/1
Jèhófà Jẹ́ Kọ́wọ́ Mi Tẹ Iṣẹ́ Míṣọ́nnárì Tó Wù Mí (S. Winfield da Conceição), 11/1
Jèhófà Ràn Mí Lọ́wọ́ Láti Borí Onírúurú Ìṣòro (D. Irwin), 10/1
Mo Láyọ̀ Nítorí Pé Mi Ò Jáwọ́ (M. Rocha de Souza), 7/1
Mo Mọ Ìdí Tí Ọlọ́run Fi Fàyè Gba Ohun Tó Ń Fa Ìbànújẹ́ (H. Peloyan), 5/1
Mò Ń Sin Jèhófà Tayọ̀tayọ̀ Bí Mo Tilẹ̀ Jẹ́ Aláìlera (V. Spetsiotis), 6/1
Nígbẹ̀yìngbẹ́yín, Ìdílé Wa Ṣọ̀kan! (S. Hirano), 8/1
Títọ́ Ọmọ Mẹ́jọ (J. Valentine), 1/1
JÈHÓFÀ
Ẹ̀tọ́ Láti Ní Orúkọ, 4/15
Ìdí Tí Ọlọ́run Fi Dá Ilẹ̀ Ayé, 5/15
Ǹjẹ́ Èèyàn Tiẹ̀ Lè Mọ Ọlọ́run? 10/15
JÉSÙ KRISTI
Àlùfáà Àgbà Tó Dá Jésù Lẹ́bi, 1/15
Àwọn Wo Ló Ń Fi Ẹ̀kọ́ Kristi Sílò? 3/1
Dídé Mèsáyà, 2/15
KÀLẸ́ŃDÀ
‘A Ò Lè Dẹ́kun Sísọ̀rọ̀ Nípa Jésù,’ 9/15
“Ẹ̀jẹ̀ Iyebíye” Ni Ọlọ́run Fi Dá Wa Nídè, 3/15
‘Jáà Ni Ìgbàlà Mi,’ 1/15
Ó Jẹ́rìí Kúnnákúnná Pẹ̀lú “Ìgboyà,” 11/15
‘Ọlọ́run Wa Lè Gbà Wá Sílẹ̀’ (àwọn Hébérù mẹ́ta), 7/15
“Ti Jèhófà Ni Ìjà Ogun Náà,” 5/15
LÁJORÍ ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́
À Ń Rìn ní Ọ̀nà Ìmọ́lẹ̀ Tó Túbọ̀ Ń Mọ́lẹ̀ Sí I, 2/15
“Àwọn Ìránnilétí Rẹ Ni Mo Ní Ìfẹ́ni Fún,” 6/15
Àwọn Ohun Rere Inú Ètò Jèhófà Ni Kó O Máa Fiyè Sí, 7/15
Àwọn Olùṣọ́ Àgùntàn Tí Wọ́n Jẹ́ “Àpẹẹrẹ fún Agbo,” 5/1
Ayọ̀ Tó Wà Nínú Rírìn Nínú Ìwà Títọ́, 5/15
Bá A Ṣe Lè Bá “Olùgbọ́ Àdúrà” Sọ̀rọ̀, 9/1
Bá A Ṣe Lè Máa Fọ̀wọ̀ Hàn fún Àwọn Àpéjọ Wa, 11/1
Bá A Ṣe Lè Nífẹ̀ẹ́ Ọmọnìkejì Wa, 12/1
Báwo Ni Ìgbẹ́kẹ̀lé Rẹ Nínú Ọlọ́run Ṣe Lágbára Tó? 1/1
Béèyàn Ṣe Lè Dẹni Tó Yẹ fún Ìrìbọmi, 4/1
Bẹ̀rù Jèhófà Kó O Lè Láyọ̀! 8/1
Bí Ọlọ́run Ṣe Ń Kó Àwọn Ohun Ti Ọ̀run àti Ti Ayé Jọ, 2/15
Dúró Sínú Ìfẹ́ Ọlọ́run!, 11/15
“Èmi Wà Pẹ̀lú Yín,” 4/15
Eré Ìnàjú Tó Dára Tó sì Ń Tuni Lára, 3/1
Ẹ Jẹ́ Kí Ọwọ́ Yín Le, 4/15
Ẹ Jẹ́ Olóòótọ́ sí Kristi Ọba, 5/1
Ẹ Jìnnà Pátápátá sí Ìsìn Èké! 3/15
Ẹ Kọ Ojú Ìjà sí Sátánì, Yóò sì Sá! 1/15
‘Ẹ Lọ, Ẹ Máa Sọ Àwọn Èèyàn Di Ọmọ Ẹ̀yìn, Ẹ Máa Batisí Wọn,’ 4/1
Ẹ Máa Fi Ìfẹ́ àti Ọ̀wọ̀ Hàn fún Ara Yín Nípa Kíkó Ahọ́n Yín Níjàánu, 9/15
Ẹ Máa Mú Sùúrù Bíi Ti Jèhófà, 2/1
“Ẹ Máa Ṣe Ohun Gbogbo Láìsí Ìkùnsínú,” 7/15
Ẹ Má Ṣe Fàyè Sílẹ̀ fún Èṣù, 1/15
‘Ẹ Pa Agbára Ìmòye Yín Mọ́ Délẹ̀délẹ̀,’ 3/1
Ẹ Sọ Ẹ̀dùn Ọkàn Yín fún Ọlọ́run, 9/1
“Ẹ̀rí fún Gbogbo Àwọn Orílẹ̀-Èdè,” 2/1
“Ẹ Ti Gbọ́ Nípa Ìfaradà Jóòbù,” 8/15
Ẹ̀yin Èwe, Ẹ Pinnu Láti Sin Jèhófà, 7/1
Ìfẹ́ Máa Ń Jẹ́ Kéèyàn Nígboyà Gan-an, 10/1
Ìgbéyàwó Tó Ní Ọlá Lójú Ọlọ́run àti Èèyàn, 10/15
Ìgbàgbọ́ àti Ìbẹ̀rù Ọlọ́run Fún Wọn Ní Ìgboyà, 10/1
Inú Orílẹ̀-èdè Tí Ọlọ́run Yàn La Bí Wọn Sí, 7/1
Iṣẹ́ Àbójútó Tí Ọlọ́run Ń Ṣe Láti Mú Ìpinnu Rẹ̀ Ṣẹ, 2/15
Jèhófà Máa Ń Gba Àwọn Tó Wà Nínú Ìpọ́njú Sílẹ̀, 7/15
Jèhófà Ń Dá Àwọn Olùṣọ́ Àgùntàn Lẹ́kọ̀ọ́ Nítorí Agbo Rẹ̀, 5/1
Jèhófà Ń Fi “Ẹ̀mí Mímọ́ fún Àwọn Tí Ń Béèrè Lọ́wọ́ Rẹ̀,” 12/15
Jèhófà ‘Ń Sọ Òpin Láti Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀,’ 6/1
Jèhófà Yóò ‘Ṣe Ìdájọ́ Òdodo,’ 12/15
Jẹ́ Kí Ọ̀nà Tí O Gbà Ń Gbé Ìgbésí Ayé Rẹ Fi Hàn Pé O Ní Ìgbàgbọ́, 10/15
Jẹ́ Ọlọgbọ́n, Kó O sì Ní Ìbẹ̀rù Ọlọ́run! 8/1
Jóòbù Jẹ́ Oníwà Títọ́ Ó sì Ní Ìfaradà, 8/15
Máa Gba Ìbáwí Jèhófà Ní Gbogbo Ìgbà, 11/15
“Máa Yọ̀ Pẹ̀lú Aya Ìgbà Èwe Rẹ,” 9/15
“Mo Mà Nífẹ̀ẹ́ Òfin Rẹ O!” 6/15
Nífẹ̀ẹ́ Ọlọ́run Tó Nífẹ̀ẹ́ Rẹ, 12/1
Ní Ìrètí Nínú Jèhófà Kó O Sì Jẹ́ Onígboyà, 10/1
Ǹjẹ́ O Ti Múra Sílẹ̀ Kó O Lè Rí Ìgbàlà? 5/15
“Olúkúlùkù Ni Yóò Ru Ẹrù Ti Ara Rẹ̀,” 3/15
“Ọjọ́ Ńlá Jèhófà Sún Mọ́lé,” 12/15
Ṣé Ojú Tí Jèhófà Fi Ń Wo Ohun Mímọ́ Ni Ìwọ Náà Fi Ń Wò Ó? 11/1
Wíwá Òdodo Yóò Dáàbò Bò Wá, 1/1
“Yan Ìyè, Kí O Lè Máa Wà Láàyè Nìṣó,” 6/1
Ọ̀KAN-Ò-JỌ̀KAN
Ààtò Ìwẹ̀nùmọ́ Àwọn Júù, 10/15
Àǹfààní Wo Ni Ìsìn Ń Ṣeni? 9/1
Aṣòdì-sí-Kristi, 12/1
“Àwòkẹ́kọ̀ọ́ Ìṣàpẹẹrẹ,” 3/15
Àwọn Áńgẹ́lì, 1/15
Àwọn Ẹranko Ń Gbé Jèhófà Ga, 1/15
Àwọn Tálákà, 5/1
Ayọ̀, 6/15
Bárúkù—Akọ̀wé Jeremáyà, 8/15
Báwo Ni Ire Ṣe Lè Borí Ibi? 1/1
Bíbuyì Fáwọn Èèyàn, 8/1
Bí Wọ́n Ṣe Ń Mọ̀nà Lórí Agbami Òkun, 10/1
“Bójú Tó Àjàrà Yìí”! 6/15
Èdìdì ‘Júkálì,’ 9/15
Ẹ̀wù Onírun, 8/1
Igi Ṣẹkẹṣẹkẹ, 2/1
Ìjọba Ọlọ́run, 7/15
Ìjọsìn Tó Máa Ṣe Ọ́ Láǹfààní, 9/1
Ìlàlóye, 7/1
Kérésìmesì, 12/15
“Kí Nìdí Tá A Fi Wà Láàyè?” 10/15
Melito Ará Sádísì, 4/15
Ǹjẹ́ Àwọn Èèyàn Lè Jẹ́ Ẹlẹ́mìí Àlàáfíà Jálẹ̀ Ọdún? 12/15
Ǹjẹ́ “Àwọn Ọjọ́ Ìkẹyìn” La Wà Yìí? 9/15
Ohun Mìíràn Yàtọ̀ sí Bíbélì Tó Mẹ́nu Kan Àwọn Tó Ń Jẹ́ Ísírẹ́lì, 7/15
Ohun Tó Máa Fòpin sí Ikú, 3/15
Owó àti Ìwà Rere, 2/1
Ọ̀nà Àwọn Ará Róòmù, 10/15
“Ọ̀ṣọ́ Gbogbo Ilẹ̀ Gálílì” (Sẹ́pórísì), 6/1
Sànhẹ́dírìn, 9/15
Ṣé Ilẹ̀ Júdà Dahoro? 11/15
Ṣé O Fẹ́ Ní Àwọn Ọ̀rẹ́ Tó Dáa? 3/1
Ṣó Dáa Kí Òbí Sọ Tẹlifíṣọ̀n Di Abọ́mọṣeré? 6/15
Ta Ni Yóò Jogún Ayé? 8/15
Wíwàláàyè Títí Láé, 10/1
Wọ́n Ṣàwárí Ẹ́bílà Ìlú Àtijọ́ Tó Ti Di Ìgbàgbé, 12/15