Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Ọ̀sẹ̀ August 10
Ọ̀SẸ̀ TÓ BẸ̀RẸ̀ NÍ AUGUST 10
Orin 78
□ Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ:
□ Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run:
Bíbélì kíkà: Númérì 7-9
No. 1: Númérì 9:1-14
No. 2: Ǹjẹ́ Gbogbo Àpèjẹ Ni Inú Ọlọ́run Dùn Sí? (lr orí 29)
No. 3: Àwọn Ọ̀nà Tá A Lè Gbà Fi Hàn Pé A Dúró Ṣinṣin Ti Jèhófà
□ Ìpàdé Iṣẹ́ Ìsìn:
Orin 47
5 min: Àwọn ìfilọ̀.
7 min: Ìwé Tá A Máa Lò Lóṣù August. O lè ṣàṣefihàn ọ̀nà ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ tó sábà máa ń gbéṣẹ́ ní ìpínlẹ̀ ìwàásù yín. Tún ṣàlàyé bá a ṣe lè fàwọn ìwé náà kọ́ àwọn èèyàn lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì.
8 min: Ṣíṣàlàyé Nípa Ìjọba Ọlọ́run. Àsọyé tá a gbé ka ìwé Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run, ojú ìwé 280, ìpínrọ̀ 1, sí ojú ìwé 281, ìpínrọ̀ 2.
15 min: “Dáàbò Bo Àwọn Ọmọ Rẹ Lọ́wọ́ Àmúlùmálà Ìgbàgbọ́ Níléèwé.” Ìbéèrè àti ìdáhùn. Alàgbà ni kó bójú tó apá yìí. Nígbà tó o bá ń jíròrò ìpínrọ̀ 4, mẹ́nu kan ìsọfúnni tó bá a mu nínú lẹ́tà September 3, 1998, sí gbogbo ìjọ ní Nàìjíríà, tá a pe àkòrí rẹ̀ ní “Bí O Ṣe Lè Ran Àwọn Ọmọ Rẹ Lọ́wọ́ Láti Kojú Ìṣòro Ní Ilé Ẹ̀kọ́.”
Orin 24