Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Ọ̀sẹ̀ July 5
Ọ̀SẸ̀ TÓ BẸ̀RẸ̀ NÍ JULY 5
□ Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ:
□ Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run:
Bíbélì kíkà: 1 Àwọn Ọba 7-8
No. 1: 1 Àwọn Ọba 8:14-26
No. 2: Kí Nìdí Tí Kò Fi Yẹ Ká Gbọ́n Lójú Ara Wa? (Aísá. 5:21)
No. 3: Báwo Ni Ìwòsàn Tẹ̀mí Ti Ṣe Pàtàkì Tó? (td 32A)
□ Ìpàdé Iṣẹ́ Ìsìn:
5 min: Àwọn ìfilọ̀.
10 min: Àwọn ọ̀ràn tó ń fẹ́ àbójútó nínú ìjọ.
10 min: Àwọn Ọ̀nà Tó O Lè Gbà Mú Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Rẹ Gbòòrò Sí I—Apá Kìíní. Àsọyé tá a gbé ka ìwé A Ṣètò Wa, ojú ìwé 111, ìpínrọ̀ 1 sí ojú ìwé 112, ìpínrọ̀ 2. Fọ̀rọ̀ wá ọ̀rọ̀ wò lẹ́nu akéde kan tàbí méjì tí wọ́n ti ṣí lọ sí àgbègbè míì tàbí tí wọ́n kọ́ èdè tuntun kí wọ́n lè mú iṣẹ́ òjíṣẹ́ wọn gbòòrò sí i. Àwọn ìṣòro wo ni wọ́n ti borí? Kí ni ìdílé wọn tàbí ìjọ ṣe láti ràn wọ́n lọ́wọ́? Àwọn ìbùkún wo ni wọ́n ti rí?
10 min: Ran Àwọn Tó Ò Ń Kọ́ Lẹ́kọ̀ọ́ Lọ́wọ́ Kí Wọ́n Lè Yẹ Ara Wọn Wò. Ìjíròrò pẹ̀lú àwùjọ tá a gbé ka ìwé Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run, ojú ìwé 261, ìpínrọ̀ 2, dé ìparí ojú ìwé 262.